POWER From Yoruba Source

POWER From Yoruba Source

Share

For Spiritual Consultation about Life Challenges and Ways for Solutions for Life Improvement

21/06/2022

MAYIUN TODAJU
Ileke itun, ileke ifa, ewe ata jije 4, ikode 1, iye aluko 1, iye agbe 1, akufo dingi die,
ewe oyo oti oyibo die, egbo ajo, irun abe obinrin, oje omun, irun ori afin eyo atare 9, iru oga.

20/06/2022

What is your take about this page

16/06/2022

WERE TABI ABISIWIN TABI KI ORI DARU
Awon omo Enia ma nse ise buburu yi sugbon ti AKUNLEGBA lo poju, Oluwa rere gba
wa, ase
1. Toba-gidi, eku asin,. Ibon eta, alubosa; ogiri jebus, baa, ipata, teyo, egbo tude, aidan,
eku oru 4, ejaro 1, ewe alupaida, ewe awogbarun, gbogbonse, isu jokoje, isu gbegbe,
epo igi agbonyin, egbo aworomaja, tewetegbo atapari ouko, egbo osunsun, egbo
ikan, iyo, egbo ibepe, iyere, egbo arutiku, egbo siferen, egbo ako yunrunyun, obi
abata jije, egbo ifon, ewe agunmona, imi ojo, egbo ito, egbo wowo, eso oti-oibo lao
fi lowon po, ao di sinu ewe, ao soro, si ibi ina, ao ma bu diedie sinu oti. Mimu nigasi
1-1 loro.
2. Ojele ewe obi, ao lo, igbin lafi se je, nigbaa 2,
3. Ewe rekureku, tete atetedaiye, ewe odundun ewe jokoje, ewe jelerunberun, ao jo
lale, ao fi ito lo o ejaro lafi se je.
4. Paku erowo, ewe eso, ewe etu, ao lo, ejaro tabi igbin la fi se je nigbakigba.
5. Ao so enyindie 1, lu igi oganlegu, lehinna, ao sa epo re, ni owo ale, ati owuro, ao se
e, mimu, OFO RE: Osinwin orun, tuja 3. Orundinnirinwo lo san ku ni ao da oruko
sinwin na, san yio.
6. Paku ito, ao fi ajala 9, ewe liborokan, ewe orowo, ao re gba ojo 7, wiwe.
7. TI A BA FE LO MU WERE: - Ewe jelerunberun, oruka irin 9, ao jo won po enyindie to
yin abo, ao da a lu, ao bu etu ti a jo lubu na sinu enyindie na, ao ko oruka na si gba

Photos from POWER From Yoruba Source's post 16/06/2022

For the Benefit of Man Kind I Sincerely Create this Page and to Testify that there is Power in Root and Animal, God actually give it to those that can take charge of it, WATCH OUT FOR GREAT BENEFITS.........

Want your business to be the top-listed Beauty Salon in Abuja?
Click here to claim your Sponsored Listing.

Telephone

Website

Address

Abuja