Ìrírí ololufe meji
Contact information, map and directions, contact form, opening hours, services, ratings, photos, videos and announcements from Ìrírí ololufe meji, Health/Beauty, Ibadan.
Ẹyin iyawa Se ẹti wọle
Ẹyin daddy wa Se ẹyin Na ti wọle
Abi odi Ago mẹwa hmmm 😜😜😜
Lotitọ Ni wipe iwa lọba awure
Mogba sugbon Mio kin Se Angeli eleran Ara Ni mi ololufẹ nibi timo ba k**i ẹfi Ife gbami bẹ oo
Ololufẹ ẹku atarọ oo
Sẹwapa ooo.
01/06/2026
Okunrin tofi ibalopo lo obinrin fun igba akoko ati obinrin to beere owo lowo okunrin fun igba akoko, tani eletan ninu awon mejeeji
01/06/2026
Mo se alabape omobinrin yi bi odun melo kan seyin oni omo okunrin meji o n gbe pelu awon obi re leyin ti ipinya ti waye laarin ohun pelu baba omo re,
O so funmi wipe ohun fee kuro ni ilu Badagry mo si gba ile fun si alakuko, ko si ohun ti omobinrin naa beere lowo mi ti mi O se fun, sugbon ko pe pupo ti iwa omobinrin yi fi yi pada simi debi wipe mo mo ninu ara mi wipe okan omobinrin naa ko si ninu irinajo naa mo, mi o le wa lo ni igba ti o wu mi O si se alabape okunrin pelu re ri, ti mo ba so fun wipe mo ni ife re ko ni da mi lohun, ko si sugbon O gba Gbogbo ona lati ri wipe ohun ko bami ja nitoripe t**i di ola Gbogbo igba ni O maa n fee fi emi imoore han
Sugbon ohun kan soso ti mo mo wipe obinrin le fun mi ni ife otito
T**i di oni ti mo n soro yi ti O ni oju awada ti mo le ba omobinrin naa se
Idi kan soso ti o fi n bamisoro di oni ni wipe ko fe ki o dabi eni wipe p fi oju oloore gungi.
Hmmm ẹ jọwọ ẹyin ọjọgbọn ẹ bami ba won Fi oyẹ Gbe Yoruba won tori Mo busy diẹ ẹ Seun gun agboyẹ yin sir/ma
゚viralシalシ
thanks for your understanding ゚viralシalシ ゚viralvideo ゚viralシfypシ゚viralシalシ
Amin ololufẹ happy new month ゚viralvideo ゚viralシalシ
01/06/2026
Olootu Inu OSU kejila ọdun ti o lọ Nimo Se igbeyawo,afa igbeyawo Yi gan Ni ,lẹhin OSU mẹfa Timo dele ọkọ, ọkọmi sọ wipe Iya oun fẹwa ma Gbe pelu wa Inu mi dun pe ma tun ma ri eyan ba sọrọ ninu Ile ti ọkọmi bati lọ si ibisẹ tan tori sef compound la nlo gbogbo rẹ ma n Dakẹ Ni ,iya ọkọmi sa De , lẹhin ọsẹ meji tiya ọkọmi De iwa ọkọmi Yi pada ninu Ile Timo ba Dana koni jẹ afi eleyi ti iya rẹ ba Da fun,ti abajọ sun sinu Yara sadede Ni maba Lori aga Ni parlour loru ,iwa rẹ Yi Kowa fẹ ye mi mọ ninu Ile Rara Moti loyun fun lẹhin igba ta Se igbeyawo tan sugbon oyun Na bajẹ Ni,Mio kọkọ RI ọrọ Na ro tẹlẹ wipe Kosi Ẹni Tiko le Dana ninu Ile sugbon oti ndi lemọ lemọ,Timo ba gba Ile mama ma tun gba won o Ni Mio gba daada ọkọmi Kosi Ni sọ Kankan ,ikan towa jẹ kin Gbe ọrọ Yi wa Sita ki awon Ara Ile ki won gbami nimoran Ni wipe koiti si ọrọ ti emi ati ọkọmi lejọ sọ gẹgẹbi ọkọ ati iyawo ti ọkọmi koni sọ fun iya rẹ, ọrọ Yi wa ma n bami ninu ati ọkan jẹ Ko tiẹ Wa jẹ ounjẹ Timo ba Se mọ ninu Ile Bai afi eleyi tiyarẹ ba Dana fun,Ni ọsẹ ti o lọ Yi ọrọ Na ,wa Di ija Larin emi ati ẹ ninu Ile,Mo Ni boya ki iya rẹ Kuku fẹ Kan ma Dana fun ninu Ile nigbayen,nigbati ounjẹ temi Koti dun mọ lẹnu rẹ,ikan towa sọ Yami lẹnu,Oni ti Inu mi koba ti dun si Kan tiya oun Se Ninu Ile oun Ilekun Ile oun wa Ni si si silẹ kin Ko ẹru mi kin ma lọ,nigba ti iya rẹ Na o sọrọ won Ni iyawo ọmọ Kan o le le awon Kuro Nile ọmọ awon oo ,Mio le sọrọ Mo kọkọ Fi isẹju marun woju awon mejeji kin to wọle lọ ma sunkun ọrọ ti ọkọmi sọ Simi ati iya rẹ,
Ẹni to bimọ tiẹ Toni kin sọ temi nu ọlọhun bami ran Nisẹ iku
Click here to claim your Sponsored Listing.