Ona Abayo Fun Awon omo omi
About omo omi omo elegies
★ ★
Kíni kii jẹ kí ènìyàn rántí awan àlá tobaun la?
Kódà awọn kàn tiẹ maùn sọ wípé àwọn kìí lala rárá hummmm,
Njẹ otitọ ni wipé awọn kàn wà tojẹ wipe wọn kìí lala rárá? kòsí ẹni ti kii lala.
Sùgbón awọn ẹdá kàn wà tojẹ wipe awọn ìka eniyán olú bá ogo ẹdá jẹ ti tojubọ kádàrá wọn láti kékeré
Torí wipe wọn jẹ ọmọ ologo idì niyi ti awọn ìka eniyán fí fi igbagbe sínú aye wọn
Nipasẹ àlá tí wón báun là torí wipe àlá má jẹ atona ìrìn àjò ayé wọn láti tètè ri ogo wọn lò láyé
Irú awọn ẹdá wọn yí kìí tètè rí ọnà abayọ sí ìsoro ayé wọn àyà fí èyí tí wón bá tètè mójú tó ọrọ ayé rẹ láti kékeré loku
Gbogbo ẹdá tí kìí bá rán tí àlà òkú ayé ní irú awọn ẹdá wọn yí kódà ẹrú (slave) ni ọpọ wọn maùn fi gbogbo ọjọ aye wọn se.
Torí wipe alá lila je ọna kàn pàtàkì ti Elédùà má ùn fi ùn bawa sọrọ nípa ìgbésẹ̀ aye wá
Awọn èniyàn kàn nà siwa tojẹ wipe wọn kìí gbàgbé àlá ṣugbọn wọn kii ní akakun lori awon ala ti wọn bá la eleyi nà tún maun fa idaamu ọjọ ọla sinu aye ọpọ ènìyàn.
Àlá jẹ òun pataki tomaun sọ nípa ano (yesterday) oni (today) ati ọlá (tomorrow) èniyan gẹgẹ bi moti sọ ní part 1
*Nínú awọn nkan ti kii tún jẹ́ ki ẹda rántí àwọn ala ti obalá ni afowofa kii ẹda ma wọ Aṣọ tii otako irawo ẹ sun odidandan kii omáṣe rántí Awon Ala tii oba ùn la ni gbogbo igba
*Bii ogún tàbí egún idile base tan lati já ẹda ènìyàn gbogbo awọn ala ti oba ùn la koni rántí
*Bii ọta basetan lati bá ogo ènìyàn jẹ wọn oni jẹ ko ranti awon Ala ee kii omabale ri ona abayọ
*Bíi ẹda ba ùn sun níí ilano totako kádàrá rẹ koni rànti awọn àlà é
Njẹ iwọ mọ pé àwọn ala kan wà tó je wipé àkíyèsí ni fún e besini odidandan kii àlá yi wasí imusẹ kódà ota àti ogun ìdílé kòní jeki ogbagbe awọn àlá yi
*GẸGẸ BII KI OMA LALÁ WIPE OHÚN FO LÓKÈ
*OUNJẸ OJU ORUN
*ÌBÁLÒPỌ̀ OJÚ ORUN
*OWÓ 💰 GBÍGBA LOJU OORUN
*FÍFI OJU KÒ OWU ALANTAKUN
*KI EGÚNGÚN MÁ LÈNI LOJU ÓÓRUN
*KI OMAA SA ÌGBÍN
*KI OMAA RÌN NÍNÚ ÒKÙNKÙN LÓJÚ ÀLÁ
*KI OMAA WO AṢỌ DÚDÚ LÓJÚ ÀLÁ
E.T.C
Awọn Ala báyìí kii un ṣe awon Ala ti eniyan le gbàgbé
ti oba tiun la awan ala wan yi tètè mura sí ọrọ àiyé ee ogún Nla ti wole.
Sugbon gẹgẹ bi moti maùn sọ fún wa wipe maje ki ogún tàbí ìsoro aye borí rẹ
Ma toríi wípé oti Gbìyànjú ni ibìkan oori iyatọ ki owa sọ wípé kòsí olododo mọ mofe ki amọ wipe eyinkule irọ ní atiun pàdé ododo, kosi bi ojú orun sema dúdú to fúnfún diẹ sima wà níbè.
Ọjọ ti oba ma pàdé ododo let me give try nani oma so ti wà fi ríi wípé ododo ni opàdé
Jekin fi awọn ọnà (road) ti aun rìn lóni se akawe fún ẹ njẹ iwọ tiẹ mọ wípé Gbogbo ọnà todi express lóni igbo ni ni ìgbà kan ríi bẹẹ gẹlẹ ni iṣoro eda
Fún Itọni lórí ọrọ ayé rẹ spiritually and physically
👇🏻
Call/WhatsApp
Fadipe Aseda care
08033784377
16/07/2026
Prayer to Òṣun for a New Day
Ìyá Òṣun, Yèyé Òṣun, Ọ̀ṣun Ṣẹ̀ngẹ̀sẹ̀,
Mother of sweetness, beauty, love, fertility, and abundance, I greet you this new day.
As the sun rises, let your sacred river wash away every sorrow, every obstacle, and every negative force from my life.
Bless me with wisdom to make the right decisions, favor wherever I go, and prosperity in all I do.
May my words be gentle yet powerful, my heart be filled with peace, and my path overflow with opportunities.
Bring loving relationships into my life, strengthen my family, and grant me good health and long life.
Let your golden blessings attract wealth, joy, and honor to me. May no evil eye, envy, or misfortune prevail against me today.
May my Ori work in harmony with your blessings, and may every step I take lead me toward success and fulfillment.
Yèyé Òṣun,
As your river never runs dry, may my blessings never run dry.
As your beauty never fades, may my joy never fade.
As your love reaches all, may favor surround me everywhere I go.
Àṣẹ. Àṣẹ. Àṣẹ.
Yorùbá Closing:
Òṣun Yèyé Kárí, Yèyé Ọ̀ṣun Ṣẹ̀ngẹ̀sẹ̀, jọ̀wọ́ gbà mí, bù kún mi, ṣí ilẹ̀kùn ìbùkún, ọrọ̀, ayọ̀ àti àlàáfíà fún mi lónìí. Kí omi ìbùkún rẹ máa ṣàn sí ayé mi láéláé. Àṣẹ.
23/06/2026
Aseja asiribibo owo kia kia
Ewe taba eyo 16
Eyin agric merin
Ao Fi ewe taba eyo mejo tele ikoko ao Fi eyin agric merin si Lori ao Fi ewe taba eyo mejo toku bomole ao se lia ni Fi omi si tio ba jina ao bo epo ara eyin ye ao shadura si ao je
Fadipe aseda care
08033784377
23/04/2026
SARA SISE FUN AWON OMO OMI
Sara yi je ohun Pataki Ninu Aye Eda Awon ti o je IPIN Omo Omi pata, Iyato wa laarin OMO OMI Ati IRAWO OMI, Eniyan leje Irawo Omi Sugbon ki o maje Omo Omi, sugbon kiise Eyi ni a Fe se Alaye re,
Opolopo Awon ti won je IPIN Irawo yi ni won koka sise Sara yi kun rara, ti sara sise yi sije Ohun Pataki Ninu Aye Eni, Melomelo Awon ti ona ti dimo, Tabi ti nkan Korogbo fun Ninu Aye ti o je wipe Aiko mase Sara yi lo nfiya je won.
Mi mose Awon sara yi je ohun ti o ma nte Eniyan siwaju Ninu Aye, paapa Gbogbo Awon ti o baje IPIN Irawo yi ni koye ki Owo (money) ki o ma won won Rara Ninu isemi Aye won, niwon igbati won ba ti nse Ojuse Awon sara yi loore koore, Oti di dandan fun won ki Aje o ma fi Ile won SE Ibugbe.
OHUN SARA
Gbogbo Ohun ti Enu ba nje bi
Ogede
Agbon
Suga
Aadun
Bisikiti
Sweet
Ireke
Etc
BI AO SESE
Ki a se Adura si Awon Ohun Sara yi, ki a wa gbe Losi Eti Odo, Tabi ki a gbe fun Awon ogo were (Children).
Ki a mu sise Sara yi ni Pataki loore koore ni sise, bi a ba Se nse Sara yi si ni ao mari Oniruru Aanu GBA ni onakona.
Iwo na Bawa share re fun Anfani Awon Elomiran
Gbogbo Iseda wa pata ni yi o ri Aanu GBA o,aseeeeeeeee 🙏.
Ire o! To .
Fadipe Aseda care 💅
08033784377
22/04/2026
ALAYE KIKUN LORI ALIJUNU TI OMA RIN ENIYON MOLÉ NI IGBA TI ABASUN (Sleep)
👩🍳🐔👳♀️
*Jin Black magic attack human being when they are sleeping*
Odara ki eniyon ma gba adura dada ki atosun (Sleep) intoripe Asikoyi ni awon Emi Okunkun mabèrè isè burukun won ni sise, Eniti kin ban gba adura dada kio to sun, Odi dandan ki awon Èmi Okunkun mada igbesi aye ré Lamu atipe Alijonu burukun Kan wa ti Oma rin eniyon molè ti eniyon ban sun (sleep) ti Oruko rè jè *( Jiwinii )* Alijonu Back magic Jiwinii ti asoro nipa rè yin, kosi isè maji ti owase ni ile aye jupe owaba igbesi aye Omo eniyon jè lo, ninu awon Alijonu burukun ti oni agbara gidi gan julo ni Jiwinii jè, Èniti Jiwinii bati rin molè hààà gbogbo ikan ni yo dojuru fun irun eniyon bè, afi ki irun eniyon bè mura si Oro aye ré gidi gan ooo atipe Oro Jiwinii koja oye Èdà,,, toripe olorun lofun Jiwinii ni agbara ti ofi da Omo eniyon Lamu... atipe tikoba si Challenges isoro fun Omo Èdà eniyon, konisi Èniti yoda olorun Oba mo gègèbi Èlèdà rè... latiri ona abayo si irun Iro yin, call me or WhatsApp
*OMO OLOGO💥👑*
*KINI CAPACITY OGO* RÈ
Ogo ju Ogo llo, Ogo gbe Ogo mi, benni Ogo ju ogo nu.
Èlomi koni Ogo sugbon Ose igbiyanju lati wa ogo ri, Osi ri OGO
Elomi ni ogo sugbon won ti Hijacked rè mo lowo
Èniti OGO ré batini problem Àtila ré yio di ogun fun😭
Obirin tikori ibujoko nile oko abi Obirin tin wo oju olorun fun omo(Agan😭) ki irun Obirin bè Mase bèru... Yodi olomo laye, call me or whatsapp
Fun ayewo Lori Irawo💥ati Akosejaye pelu Ona abayo si isoro tiakori oju rè,call or Whatsap
08033784377
Adura rè àgba 🤲🤲🤲
21/04/2026
*IYATỌ LÁÀRIN ỌMỌ OMI ÀTI IRAWO OMÍ*
*MOTUN ATUPALE OROYI NITORI AWON TIKOYE ATI AWON TIWONDA GBOGBO RU MO ARAWON LOJU,EMABAMI KALO👇👇👇👇*
Ọpọlọpọ eda nii won ma se àsìse lori ọrọ irawọ
Njẹ iwọ mọ pé kii se gbogbo ẹnití Obanlo irawo omi nii ipin irawo wọn kò nii won je ọmọ omi
eniyan lejẹ eyikeyi irawo,gege bi apejuwe,irawo afẹfẹ kii osi je ọmọ omi bẹ nee loje fún gbogbo àwọn irawo mererin towa
Njẹ iwọ mọ pé iyatọ wa laarin irawọ ati ẹgbẹ
*IYATỌ LAARIN ẸGBẸ ATI IRAWO*
merin nii Gbogbo irawo bẹ sini gbogbo won nii won nii anfani tii won se fún arawon ni won ba igba tii won batinse awọn ikan tii irawo won fe ati eyi tii ko fẹ.
Bẹ náà nii Egbe gangan tun da dúró fún arare ejeki amu ẹnu ba ọrọ nipa diẹ ninu ee
*IRAWỌ OMI*
Irawo Omi pinsi meta gege bii Asemo sugbon kii se gbogbo onirawo Omi nii oje omo elegbe bẹ ní kii se gbogbo ẹlẹgbẹ níí onirawo omi bẹ ní kii se gbogbo ikan ti irawo omi l'eje níí ọmọ omi lè jẹ.
Gẹgẹ bíi àpẹẹrẹ;
*ẸJA 🐟 ARỌ (cat fish) JÍJẸ FÚN ONIRAWO OMI*
Kosi ikan tii oburu ninu kii onirawo omi jẹ eja aro niwonba igba tii kibati jadefun wipe omo omí ni ( elegbe ọmọ)
Oseese kii eyan jẹ irawọ ina gan kii osi tun je elegbe ọmọ
*NJE ẸLẸGBẸ ỌMỌ LÈ FI ẸJA ARỌ BỌ ORÍ* ?
Bẹ níí anfani wa fún ọmọ ẹlẹgbẹ lati fii eja aro bọ ori ṣugbọn kosi anfani fún láti jẹ ẹja aro
Anfani wa fún lati gbe fún àwọn eyan kii won je amo kogbodo je eja aro
Bẹ sini anfani wa fún onítòhún kii ologbe ẹja 🐟 arọ yìí sì inu odo.
*AKOBA FUN OBINRIN TI OJE ẸLẸGBẸ ỌMỌ*
*mase je ẹja 🐟 aro
*Mase b'awọn pa eja aro
Púpọ nikọ mọ pé ẹlẹgbẹ ọmọ níí oun ṣugbọn Aini àkíyèsí níí on koba
Mase bawon jẹ ọgẹdẹ 🍌 abalaye
*NJẸ ÈYÁN L'ẸJẸ ONÍRÀWÒ INÁ KÌÍ OTUN JẸ ỌMỌ OMI* ?
Bẹ níí ṣugbọn ti owa nibe ni wipe bíi koba níí anfani lati ma se saara ti opapo mọ ìpín iseda irawo ee tabi kii oma fún àwọn Egbe ee nii ounjẹ oseese kii iru won mase ẹrú Egbe won
Gbese yóò pọ fún wọn lẹnu iṣẹ wọn
Eyini awọn ọna tii onirawo ina yóò ma fii mọ pé ọmọ omi nii ohun.
Oseese kii omi máa sun jade nii ẹsẹ rẹ nii gbogbo igba
Kii oma lala pe ohun wa ninu ọdọ pẹlú àwọn eyan ti ọ pọ gan
Etc....
*IRAWỌ ERUPẸ*
IWỌ tii oba lo ipin iseda ERUPẸ fúnfún VIRGO ♍ moki e ku orire nitori gbogbo yin nii iseda yin jade latara okun idi niyi tii ofijepe ni opolopo igba ayewon amani itumo,ṣugbọn egbiyanju kii Ese àwárí arayin latara iwa ikora enii nijanu ti kii esora fún iwa agídí kii je ra yin lewulo latara ẹgbẹ tii ẹwà
*NJẸ ÀKÓBÁ WÁ FÚN ONIRAWO ERUPẸ TI OJẸ ỌMỌ OMÍ*
Àkóbá wà fún oníràwò ni won ba igba tii oba tii je òun ti olodi síi ipin irawo ee
Bẹ sini kogbodo je ikan tii olódì síi ikan tii Egbe korira ati wipe bíi iru wọn bá n huwa idoti odidandan kii Egbe ma fii won fún ìyá jẹ
Leyin naa yatọ síi eyii onirawo erupe kogbodo se ikan tii otako ipin iseda irawo ee .
Gẹgẹ bí àpẹẹrẹ àwọn iseda irawo kan wà tó jẹ wọn
* kogbodo sun ni ìhoho
*Won kogbodo je ikan ti oba fi aya wọ nile
* Kogbodo sun sinu okunkun
*Won kogbodo wo aṣọ dúdú sun
Pen by
Fadipe Aseda care
FOR ANY COMPLAIN OR QUESTION 👇👇👇
08033784377
20/04/2026
MORNING PRAYER 🤲
You will not be disgraced in life🙏
Whosoever that is waiting for you to fail so as to laugh at you and say, I said it.
May your Head cause them to wait forever in vain, and whoever takes your name or picture to evil altars with the intention of harming you, may they never return from that journey alive
Ase edumare ✊✊✊
19/04/2026
AWON APERE TI AFIMA ENIYAN TI OKO TABI AYA ORUN NDA LAAMU (INCUBUS & SUCCUBUS)
1-Obinrin tii oko orun ba nda laamu gbogbo igba nii yio ma la Ala ibalopo loju orun, iruwon kini ade ori, ijakule ni oma ri lodo awon okunrin toba nfe, elomiran ninu won okin ntete ri omo bi...
2-Besini tiwon ba nii oko osese kii okowon mari ifaseyin lenu ise nitoripe oko orun amabinu sii oko Aiye tiwon fe.
3-Ti okunrin ba ma nfi ara ko owu alantakun daada, osese kojepe aya orun lo nda laamu nitoripe ijakule nii yio masele si ni gbogbo igba... Osese koje ipe aya orun ndamu iru eniyan be....
4-awon eniyan yi ama Saba maa lala ibalopo loju orun tii asima gbadun re ju tii oju aiye lo.
5-Iruwon kii nsaba tete rii omo bii loju aiye sugbon Inu egbe ni won ti bimo Repete fun oko orun, idi niyi tii won fii ma nso fun obiinrin miran pe oti bimo daada tii asima jiyan pe on kobimo rii...
6-oko orun tabi aya orun won okin fefi won sile rara torire ni won okin fi tete ri ona abayo si isoro yi, opolopo won gan okin tete ma ibiti oye ki awon ti ri ona abayo si isoro won tori awon spirits tabi alujannu yen.. Yio ma siwon lona ni....
7-Wahala nla nifun okunrin Tii obani Aya orun Nitoripe kowopo ninu awon okunrin Tii Oni aya orun sugbon eyii tii obani kii nsaba ma nse Aseyori pelu Awon Obinrin tii obanfe
Ija Loni ijalola nii, kii se ejo on naa biki sepe Awon isoro Aiye re nii...
8- konisi ilosiwaju kankan fun iru awon enibayi. Yala nibi ise tabi Inu Ile
9-Iruwon kii saba ma nkonu sii obinrin nitoripe won okin ri ti obinrin roEru ma nbawon.
10-Iruwon ma nsaba ma n ma******te dipo kii won nii Ibalopo (s*x ) pelu obinrin nitoripe nkanyii ma ndun mawon gan
Awon elomiran ninu kii saba gbe nkan rere se laiyedebipe omo wani owo(money) ni owo, besini koni ri omo bi.. Oro re awadabi ejo tokoja Lori Apata tiko nipa.. Ki olohun sowa nibe 🙏
MAJEMU TII PUPO NINU ENITI OKO ORUN NDA LAAMU MA NDA FUN OKOWON LORUN KIWON TOWASI AIYE
1-Elomi Ma nfi ọjọ́ ikùnlè ( labouring day) búra wipe ojo yii nii oun yio pada...
2-Elo miran ma unfii ojo igbeyawo( wedding day) bura wipe ojo yii nii ohun yio pada si arin won..
3-Elomiran masope ohun koni ni ololufe kankan nile aiye tohun nlo yi.. Sugbon tobade ile aiye tan yio ti gbagbe gbogbo adehun, ibiti wahala tima bere niyen..
4-Elomi ma sope tio oun bati pe iye odun bayi nile aiye ohun pada bo....ETC....
Eje Kin Nda Denu (✍️) Duro Bayen Na....
MESSAGE MI LORI WHATSAPP PELU NUMBER TOWA LORI PROFILE MI FUN IWADI (CONSULTATION)
FADIPE ASEDA CARE 💅
08033784377
Click here to claim your Sponsored Listing.
Category
Website
Address
Ilesha