Orisun Iwosan

Orisun Iwosan

Share

This is correct place for your Health issues

05/01/2026

OGUN ULCER TO CONFIRM:

Ewedu oojo, Oyin gidi. A o se ewedu yi pelu Iru ati Iyo sugbon a o ni fi Ata si. A o wa ma mu ewedu yen die die l'aro ati ale, a o se be fun Ojo meta. Leyin igba taba ti mu Ewedu yen tan a o ma la Oyin gidi yi ni sibi meji l'aro ati ale.
A o ni fi aisan l'ogba.
Fun ibeere: 07069685743.

28/02/2024

Ogun Eyikeyi Iko Todaju:

Omi Idi Igbin die, Omi Orombo die, Oyin gidi die.
A o da meteta papo, tiko ni jur'awon lo, Agbalagba o ma lo ni sibi meta laro sibi meta lale, Omode o ma lo sibi meji laro ati ale.
A o ni fi Aisan logba.

Fun Alaye/Ibeere: Call/WhatsApp:07069685743.

10/12/2023

Ogun Belubelu

Ibepe to pon dada ao fi etu ibon oyinbo pa ibepe yi lara a o ma je, ni agbara olorun Beluvelu na yo san. A o ni fi Aisan logba.
Fun ibeere/Itosona: 07069685743.

10/12/2023

Shout out to my newest followers! Excited to have you onboard! Princess Adeboye, Wahab Abd Afeez, Adeleke Égùkékéré Alamissi, Sulaimon Owolabi, Babajide Adebayo BF, Oyeyemi Oyetola, Muhammed Saka, Call Mhi Kehinde Olakiitan, Aworo Sasa Holy Man, Aduni Olawepo, Opeyemi Omowumi, Jelili Idowu, Lolly Frosh, Agbaluasa Oyo, Agnes Quadri, Quazeem Ariyo, Abdullahi Andulhamid, Prince Adeyinka, Fela Egba, Iyabo Saheed, Abdul Rasheed Kewulere, Hassan Ajibola

20/08/2023

Ogun Inu Rirun.

Oronro Ejo Oka tabi Oronro Malu, a o ko opolopo Eyo Atare sinu re fun Ojo Meje. A o ma je Atare yi t'inu ba run wa.
A o ni Aisan l'ogba.

Call/WhatsApp: 07069685743

26/07/2023

Ogun Akokoro

A o gbe Omi Osan Wewe kana, a o je kofe gbe lori Ina, a o ju Kahun Bulala si, a o fi Owu Cotton Wool si to ba tutu, a o ma dimo Eyin ti Akokoro wa. Pelu ogo Olohun Eyin na koni dun wa mo.

Call/WhatsApp: 07069685743.

24/06/2023

Agbo Iko fun Omode ati Agba.

Eru Alamo, Egbo Igi Oruru, Ogede wewe pupa, Ewe Omisinmisin Gogoro, Ori die. A o fi Omi ki l'agbo, A o ma mu ni cup kookan laaro, losan ati ale.

Akiyesi: Omode idaji cup, Agbalagba cup kan.
A o ni fi Aisan l'ogba.

Call/WhatsApp: 07069685743.

15/06/2023

Agbo Iba todaju

Ewe tea, Omidun, Osan wewe, ati Epo igi kashu, a o fi ewe yi tele koko, a o ko epo igi kashu le, a o ge Osan wewe si, a o da omidun si, a o se ti o jina dada. A o ma mu die die.
A o ni fi Aisan logba.

Call/WhatsApp: 07069685743.

08/06/2023

Ogun Èda:

A o wa ose dudu die, a o fi oje lapalapa funfun si ti o fi ro dada, Obinrin na yo ma fi fo abe lale ko to sun. Pelu ogo Olohun Arun Èda yen o ni dalamu mo.
A o ni fi Aisan l'ogba.

Call/WhatsApp: 07069685743.

24/04/2023

Ogun Eje riru (Hypertension).

A o wa omi iru, eyi ti won fi se iru jina, bi dede 5liters. A o ra Alubosa Ayu to po a o ge sinu re, a o tun ra Egbo Akogun a o da sinu re. A o gbe kale fun ojo meta kato ma mun. A o ma mu ni cup kookan laro ati ale.

Akiyesi: Alobosa Ayu yen gbodo poju Akogun lo.

Fun alaye ati ibeere:07069685743.

A o ni fi Aisan lo gba oo.

18/04/2023

Ogun Kokoro inu eje:

A o lo Akogun ti o kunna dada, a o ma bu sinu osan wewe ni sibi kokan ni ojoojuma, a o ma gbemu. Eni ti o ba ni ogbe inu (ulcer) yo ma bu sinu omi tutu, kogbodo lo osan wewe.

Fun alaye ati ibeere: 07069685743

Want your business to be the top-listed Beauty Salon in Ilorin?
Click here to claim your Sponsored Listing.

Telephone

Website

Address

Ilorin