Asiri Imule Ola Family Backup
prayer is the key to success contact me for any kind of prayers on all spiritual problem 09036965046
OGUN AWURE FUN CONNECTION LATI FI MAA RI OWO(MONEY)
Abo adie dudu nla kan,
eye lekeleke kan,
ori olongbo kan,
ori oka to ni ase l'enu kan,
ori ere to ni ase lenu kan,
ikoride kan,
iye agbe kan,
iye aluko kan,
atare nla meta,
itun,
ifa,
abere to po die,
irun woro to po die,
ewe ejirin to po dada.
SISE RE:-A o la inu adie na, a o gbe adie na sinu ikoko ijoogun ti a o si oju adie na soke, a o wa ko gbogbo eroja toku le lori, a o wa da ewe ejirin bo mole dada, a o wa jo dada, ti a ba ti jo tan, a o lo ti yoo kunna dada, a o wa ro sinu igo funfun kan.
LILO RE:- a o ma fi oti schnapp original lo larolaro.
OFO RE:-a o ma sope bi a ba fa gburu,gburu a fa igbo, eni to momi ki won lo pe eniti ko momi ki awon mejeeji maa ko owo nlanla wa fun emi lagbaja omo lagbaja(a o daruko wa ati oruko iya wa).
22/12/2025
OSHE-OSHOLE NLA
Oshole 5m Yi je okan Lara awon ise to Yara sise dada kosi eni tiko lese ise Yi yala okunrin tabi obinrin, Oda fun awon omo Ori afefe na dada pelu awon onisowo, enikeni Toba je onigbiyanju kodan ise Yi wo konilo Imule tabi eyonu nitori ise yi gan imule ni fun rare loto
Koni ipalara kankan ninu tabi saara Tama se
Ise todaju tosi confirm dada ni pelu iyonda olohun
Ao sa okuta arin-oja eyo mesan(kobaje okunrin tabi obinrin lofe se okuta mesan la gbudo lo)
Ewe aje oojo tabi tutu
Iye lekeleke meji,
Odd atare kan
Itun
Ifa
Abere
Ikode kan
Ori eiye igun kan
Ase okete meta
Ao jopo ninu isasun tuntun,ao gun papo mo ose ibile Toba wuwa
Ao ko sinu isasun ti a fijo yen,ao da lofinda bintu si lori. Ao gbe sori osuka a*o ff.ao gbe pamon fun ojo meje,leyin ojo keje.odi wiwe laro laro.Akiyesi:----- Ao lo okuta mesesan yen kuna looto nio,ao wa dapo mon eyi ti a jo,aosese wa po mon ose.
Click here to claim your Sponsored Listing.
Category
Contact the business
Telephone
Website
Address
Kwara
240101