Asiri mimo ayanmo ti o gbe waye
Moki gbogbo awa ta wa ninu yara yi wipe, adura enikokan wa a gba. Ninu group, a o ko ara wa ni opolopo nkan ti o ma sewa la n fani pupo.
moki gbogbo yin ninu ile yi... E ma binu simi wipe, mi o ti fi asiri naa sile.... Mo fe ki awon eyan pupo je anfani asiri nani.. Nitori e lose pe die.... E bawa invites awon ore yin naa sinu ibi.... Won o ni kaba mo wipe, e invites awon sinu bi. E se pupo
A o ma fi awon asiri kan sile fun gbogbo wa lati je anfani re. E jowo e bami invites awon ore yin naa sinu group yii, ki awon naa le je anfani naa
ekaaro ninu ile, aku osu tuntun. Mo gba ladura pe, Ayo, ibukun ati Alafia ni a fi se osu na.
Ekale ninu yara yii.... Aji layo oo
Click here to claim your Sponsored Listing.
Telephone
Website
Address
Lagos