Agbara Aseyori
Oro nipa igbesi aiye ,oniranran eto bi ayewo sise ,eto igbiyanju sise
06/02/2024
ASIRI ARISIKI GBOGBO NISE IRAWO
TO GBONA JANJAN No1.đŻđŻđŻâïž
# # # ASIRI ATUDE GBOGBO IDE AIYE.
# # # ASIRI ASINA NLA.
# # # ASIRI AWURE ARISIKI.
# # # ASIRI ANU NLA.
# # # ASIRI ISEGUN NLA.
# # # ASIRI AMUNBO.
# # # ASIRI IBUKUN NLA.
# # # ASIRI AGBA IFERAN.
# # # ASIRI AGBA IMUNLE No1.
(1)*** EYIN-IBILE TOMO DAADA KAN
(2)*** IYO-OLOKUN TI WON TIDI SORI ATE EYO KAN PERE #50 NAIRA NI.
Ni dede agogo mejila oru ojo Sunday mojumo ojo Monday ni amasa.asiri Ise yi oooo, a o boo gbogbo a*o ara wa kogbodo si inkankan lara wa oooo, ihoho omoluwabi lagbodo se akanse Ise yi oooo, a o tuu iyo naa pelu gbolohun yi wipe, ASIRI LADIYO (3*) TI ENIKAN BADIYO LOJA, IGBA OWO NITU TOBADELE, GBOGBO IDE AIYE LARA EMI____ OMO____ MOTU WON LONI YI OOO,,, a o tuu iyo naa, a o dasi ilele ninu yara wa, a o fowotan kole gba iduro wa, a o wa duro lori iyo naa, .a.o wa do eyin naa sinu ike kan, a o fi gbogbo eyin naa paa gbogbo ara wa latori t**ide ese wa, lesekese a o maa bere oun gbogbo ti abanfe, a o si mako gbogbo oun ti akofe, a o se eleyiwo ago kan gerege 1:00 Am. Oru, lesekese a o ko awon iyo ti aduro le lori, sinu ike garawa omi toto wa sanra, a o gbodo runra ri abati wetan oooo, tobadi ojo keji a o lose itore anu fun alagbe, asiri yi data pupo lekan losu, gbiyanju re so loni ninu EPE tabi ADURA jowo fun mi nikan nibe oooo, dandan ni ki o pelu awon OLORIRE KORIN AYO SI OLORUN ATORISE....
YOBAWA LARAMUN LAGBARA OLORUN ASE TEDUMARE..
Gbiyanju lati share oseyi si group Miran koleje fun oooo manjemun ree in
Fun iwotiobani ipenija kookan tabi iseyi wu oooo lati see sungbon kosi ayeee pemi tabi kio message me Lori WhatsApp number mhi
((( 08147277409 )))
06/12/2023
ADVICE .......
DECEMBER WHY DID WE BELIEVE THAT DECEMBER IS THE DANGEROUS MONTH (OSU BABABA) THAT IS POOR MAN THINKING.
YOU THINK IS THE MONTH MONEY RITUAL RENEW THERE MONEY đ (POOR MAN THINKING) THE MONEY RITUAL THEY DO ON OCTOBER JULY CAN'T BE RENEW ON DECEMBER . THINK VERYWELL .
LET ME TELL YOU A LITTLE SECRET YOU DONT KNW ABOUT DECEMBER .
AS A BUSINESS PERSON ARE YOU NOT PREPARING TO SELL THINGS IN DECEMBER . WHY ? IS THERE NO OTHER MONTH ?
SOME PEOPLE'S WILL NOT THINK THAT 2023 AS GONE . BOOOOOOM DECEMBER COME THEY WILL START THINKING ABOUT THEIR LIFE. THEY WILL WANT IT TO TURN AROUND WITHIN THE BLINK OF EYE đ .
DECEMBER IS THE MONTH MOST PEOPLE'S TAKE THEIR LIFE SERIOUS .
DECEMBER IS THE MONTH MOST PEOPLE'S. START A JOURNEY ABOUT THEIR LIFE
DECEMBER IS THE MONTH MOST PEOPLE'S BUSINESSES BOOOOM
NOTHING DANGEROUS ABOUT THE MONTH .
BEFORE MONTH OF DECEMBER THEY ARE KIDNAPPING . PEOPLE'S ARE DIE .
THIS DECEMBER DONT THINK NEGATIVE THING ABOUT IT .
THINK POSITIVE.
THINK ABOUT HOW TO MOVE YOUR LIFE
THINK ABOUT HOW TO USE YOUR NEW YEAR
IF YOU HAVE PLAN A ALWAYS HAVE PLAN B
ASEYORI
Follow agbara aseyori for more
https://www.facebook.com/profile.php?id=100085469490457&mibextid=ZbWKwL
Get honey đŻ Put it in your mouth early morning without talking to anyone, and bless yourself and your family
AGBARA ASEYORI
Update. First use imule the 1th week . 2th week use eyonu . 3th week use osole đȘđȘđȘ December code
Agbara aseyori
02/12/2023
OJO TIPE TIWO TI SE OGUN-OLA,
OJO TIPE TIWO TI SE OSHOLE-OWO,
OJO TIPE TIWO TI SE IMUNLE ASINA OWO NLA, SUGBON KAKAKI EWE-AGBON REDE, LILE KOKOBI KOKORIN LOTUN JASI, JOWO SUNMOMI NITOTI, ARANMI SI O NI, OWO KOSE MANI, OSI KOSI SESE GBAJUMO NIGBORO ASIRI AWON OJOGBON TI WON FISE ILE AIYE WON NINU IRORU, LAIWA ORI OLORI KIRI, LAIFI ERAN OMO ENIYAN SETUTU OLA, ASIRI YI, KONAWA NIMUNLE KOTODI PE OSISE IYANU RE OOO, MOFI ILEAIYE MI BURA FUN YIN, ENITOBA LO ASIRI YI GBUDORI OWO BIOLE NI, YORUBA NI ENITI YO BOSO SINI LORUN TORUN RE LAKOKO WONA,,,,, OPOLOPO WA LOTIMOMI DAADA KOTODONI TORI ODU NIMIN EMI KOSE AIMON FUN OLOKO, DAN ASIRI YI WO NAA, NINU EPE TABI ADURA EFUNMI NIKAN NIBE..........
ASIRI OSHOLE OWO NLA OGUNDABEDE, TIMUN NI GBOWO BIOLE, TESTED AND CONFIRM đŻđŻđŻđŻâïž
(1)*** PEYE IBILE KAN.
(2)*** OMO-ONIGEDEGEDE DIE
(3)*** OWO-EYO TI KOLUJU 16.
(4)*** OTI LORD KAN.
A o lo owo-eyo ti koluju merindinlogun 16, a o teni ifa-ogundabede leyin naa, a o daa oti Lord kuro ninu igo re sinu abo NLA kan, a o paa pepeye funfun naa, a o roo eje re lori oti naa tan, a o daa eto.owo-eyo ti atilo eyiti atite ni ifa-ogundabede sinu igo oti lord yen, a o ko omo-onigedegede le lori, a o daa oti ti ati paa eje pepeye yen sinu igo naa pada, a o se opolopo adura OWO NLA sinu oti naa, a o depa,a o gbepamo fun ojo meje 7,days, leyin ojo meje yi, a o mamun ni gasi kokan lararo, ni akoko ti afinlo ise yi, seni a o MAGBA owo biole ni oooo
ASIRI YI DARA FUN GBOGBO ENITI OBANI ISE LOWO, ONA OWO NLANLA YOMALA FUN WA, PAPAJULO, AWA TI AMADA AWON ALEJO LOHUN, KOSI ENITI KOLE LO ISE YI OOO, NI AKOKO TI ABALO ISE YI, DANDAN NI KI ARIOUN RERE GBESE NILE AIYE WA TO DAJU,,,,,
YOBAWA LARAMUN LAGBARA OLORUN ASE TEDUMARE.......
: RIDAJUPE O SHARE ISEYI SI GROUP MIRAN KIWONLEJE ANFANIREE KOLEJE FUN OOO MANSE AFOJUDI DUPE MANJEMUN REE NII {{{ 08147277409 }}}
FUN IWOTI ISEYI BAWU LATISE SUNGBON TIKOSI AYE PEMI TABI KIO MESSAGE ME LORI WHATSAPP TABI AYEWO LORI ORO IGBESI AIYERE 08147277409
follow me on my page for more knowledge
https://www.facebook.com/profile.php?id=100085469490457&mibextid=ZbWKwL
29/11/2023
SPIRITUAL SPOUSE
SPIRITUAL HUSBAND IS DIFFERENT FROM SPIRITUAL SPOUSE
when we talk about spiritual spouse,
Your spiritual spouse is your twin . Sometimes we call them angel
Please you can never separate yourself from your spiritual spouse, whoever told you that is making things more difficult for you.. ask those who have spend much money on it
You go for appeasement,
You go for pleading
that you should be allowed to live a normal life here on earth..
Even if you face it with prayer . It will be under appeasement or pleading
Spiritual spouse,if not acknowledged and appeased,does a lot of hurtful things, likeđ
Disappointments..
Failures..
Setbacks..
Hatred..and many more.
Do yourself the best thing by appeasing your spiritual spouse so you can live a comfortable life..
There are items that are needed for appeasement,
as a woman, you appease your spiritual husband.by paying back your Dowry .
As for men appeasing their spiritual wives, there are some important spiritual items needed too.
Some spiritual spouse demand for goat . đ . Fruit . And some item's but not all, before anything, always find out from Afa consultations to know wat they demands,so you don't make mistakes.
Also check your river of reincarnation,as a chosen one,
Another important one,is the market day your Chi will be available to accept your sacrifice. I use to tell people this but some believe some don't.
very important.
Not only mariners there are some many egbe .
because everyone actually came out from somewhere..
check yourself and be free.
AGBARA ASEYORI
Follow me on my page for more knowledge
Some egbe that someone have that is torment are life . Is the same egbe someone have that is helping are life
20/11/2023
EKUATARO EJE KA LO GBINYANJU ISE ODAJU OOO...
OSOLE TORIN TAARA
Ori Okete 1
Ori Olongbo 1
Odidi Atare Nla 2
Eyin Ororo Tomo 6
Ewe Ejirin
Oga oyeee Nla kan
Owo tuntun kan
Aofi oga yii pelu owo tele inu ape ijogun
Aomu ewe Ejirin yan aosu bii osuka sinu ape,aogbe Ori Olongbo yan le ori ewe yan, aogbe Ori Okete naa si aoko oju mejeeji sirawon,aofi odidi atare mejeeji si ni egbe otun ati osi,aojo papo,aowa da etu re si meji,aopo idakan mo ose dudu,aoda idakeji sinu oti schinap,aomaa fi ose we ni araaro,tia ba we tan aomaa mu tinu schinap yan,odaju sugbon olorun daju juulo.
:RIDAJUPE O SHARE ISEYI SI GROUP MIRAN KIWONLEJE ANFANI REE KOLEJE FUN OOO MANJEMUNRE NIIIII
Follow me on my page for more benefit on AGBARA ASEYORI EDA
°°TABI EFE IBEERE TABI FUN IRANLOWO LORI ISORO ABI OGUN TI EDAJUKO . .PESORI NABA MI TABI KOBAMI SORO LORI WHATSAPP 08147277409
IF YOU WANT TO ORDER MY PRODUCTS?
°° YOU HAVE ANY QUESTIONS ON WHAT WE POST
°° OR YOU NEED HELP ON ANY SPIRITUAL PROBLEM OR WAR THAT YOU ARE FACING CALL OR WhatsApp {{ 08147277409 }}EKASAN EKUATARO EJE KA LO GBINYANJU ISE ODAJU OOO...
OSOLE TORIN TAARA
Ori Okete 1
Ori Olongbo 1
Odidi Atare Nla 2
Eyin Ororo Tomo 6
Ewe Ejirin
Oga oyeee Nla kan
Owo tuntun kan
Aofi oga yii pelu owo tele inu ape ijogun
Aomu ewe Ejirin yan aosu bii osuka sinu ape,aogbe Ori Olongbo yan le ori ewe yan, aogbe Ori Okete naa si aoko oju mejeeji sirawon,aofi odidi atare mejeeji si ni egbe otun ati osi,aojo papo,aowa da etu re si meji,aopo idakan mo ose dudu,aoda idakeji sinu oti schinap,aomaa fi ose we ni araaro,tia ba we tan aomaa mu tinu schinap yan,odaju sugbon olorun daju juulo.
:RIDAJUPE O SHARE ISEYI SI GROUP MIRAN KIWONLEJE ANFANI REE KOLEJE FUN OOO MANJEMUNRE NIIIII
Follow me on my page for more benefit on AGBARA ASEYORI EDA
°°TABI EFE IBEERE TABI FUN IRANLOWO LORI ISORO ABI OGUN TI EDAJUKO . .PESORI NABA MI TABI KOBAMI SORO LORI WHATSAPP 08147277409
IF YOU WANT TO ORDER MY PRODUCTS?
°° YOU HAVE ANY QUESTIONS ON WHAT WE POST
°° OR YOU NEED HELP ON ANY SPIRITUAL PROBLEM OR WAR THAT YOU ARE FACING CALL OR WhatsApp {{ 08147277409 }}
19/11/2023
â
AKIYESI_NIPA_IRAWO_OMI_MEJIâ
bi iseda omi Ă ti omi bĂĄ Fera wá»n. Ama dĂčn be sini ama lalafia sungbon fĂșn ĂŹgbĂ diÄ ni. NĂ fĂfe wá»n. Ohun toye ki won lo mon saju ki won to Fera won ni kĂ wá»n lá» nĂ imo ni pĂĄ Akosejaye Ă won mejeji torĂ kosi bĂ wĂł. Sele gbĂ© ra wá»n sĂŹ lĂš tĂ wá»n o niri alebu ara won.
Awon nkankan wĂ toye ki won ni akie ĆiĆĂ.
*ki won loni imon nĂpa ibalopo ara won torĂ ĂČnĂ asiko toye ki won mĂĄ wá»lĂ© tĂ arawon bibe ko opo igba ni iseda meji yi mama fi ra won sile
*ki won loni imo nĂpa akosejaye ara won tori iseda yi mari isoro ibujoko ati ĂŹáčŁĂČro á»ká» orun bi won koba wa di ara won dada opo igba ni igbeyawo won amatuka. Ti won sini mon ibi ti ogunti wole ti awon.
*ki won loni imo nĂpa a*o Wiwo wá»n irawo meji yi ni lati wa imo nipa Akosejaye A*o ara won. Toje loky colour won.
*ki won loni imo nĂpa ilĂș tĂ wá»n legbe Ăti ohun toye kĂ wá»n Će. Ati ise asela wá»n.
* ki won loni imon ni pĂĄ ĂgĂșn ĂŹdĂlĂ© tĂ oun bĂĄwon ja. Bibee kĂČ koni si Irepo fĂșn Awan oni irawo yi besini Ă ti je eniyan won yio nira.
TĂ ISEDA yi bawa Fera wá»n sĂlĂš wan ma damun lopo ĂŹgbĂ torĂ egun idile amada won lamu. Abi koje oko orun abi aya orun ikan amasele si won.
Beesini tĂ wá»n kĂČ bĂĄ mon nĂpa Akosejaye ara won aigbora eni ye ama sele eleyi sile fa ipinya laarin awan mejeji ni kia kia.
Besini kadara mi wa ninu awan irawo omi meji toje wipe odĂșn marun ni gbigbe pĂČ wan mon ibagbepo wan koju odun marun lo omiran odĂșn meta tĂ ĂŹpinya mafi waye laarin wan.
Awan iseda yi nkan maun tete suwon. Suru lĂłye ki eni Besini ĂŹfaradĂ lo se koko fĂșn yĂn. Ki iseda yi si maa se sĂĄra dada.
Awan iseda yi wan kii pe ri alebu ara wan Toba pĂ© t**i eni Kan nĂnĂșn wan magbe igbĂ iranun
Awon irawo omi won yi ti won ko batete mura si oro aye ara wan dada nkan mapada le fun ruwon iseda meji yi nilo lati mu suru ati imonra eni dada. Irawo omi yi abo irawo ni. Besini won ni lati mo iru áșčgbáșčÌ ti Ă wá»n wa.
Irá»run l'afi parĂ odun t'awa yĂŹĂ Ă ti ĂšyĂ tĂ afi mĂș yii amen awan Ă gbĂ lagbĂ nĂ to ĂČgĂšdĂš ba pá» t'inu ráșč a dĂ© yo dĂ© fĂșn Gbogbo wĂĄ lowo lá»la ki odun yii to pari bami sa ameen ĂĄdĂčrĂĄ yii ki share re fun Gbogbo eniyan
WhatsApp/Call
08147277409
19/11/2023
OMO TO N DAKU DAJI TABI TI O MAA N SUNKUN WA LATI OJU ORUN NIGBA GBOGBO
Mi o raaye a*odun
Oju omonile otun a o lo pelu eyo atare Kan a o Fi sin gbere Kan si isale oju otun omo naa, oju omonile OSI a o lo pelu eyo atare Kan a o Fi sin gbere Kan si isale oju OSI omo naa lobatan
Ikilo : a o gbodo lo ise Yi ni oju olo Kan naa o to tumo SI wipe a o lo oju otun Lori olo Kan oju OSI Lori olo Miran
GBIYANJU LATI SHARE ISEYI GROUP MIRAN YIOJE FUN WAAA
FOR MORE FOLLOWE ME ON MY PAGE https://www.facebook.com/profile.php?id=100085469490457&mibextid=ZbWKwL
FUN IRANLOWO MESSAGE ME ON WHATSAPP OR CALL ME {{ 08147277409 }}
Click here to claim your Sponsored Listing.