IWO LOKAN

IWO LOKAN

Share

Sanyo bus-stop ibadan

23/07/2022

Iba ni moju fun awon ajunilo

24/06/2022

Join awal whatsspp number,08163893817

22/05/2022

AWORO KAN TUNRE
Aowa eru alamon topo die,Alo Kun na dada,aopo iyo isebe die mo,aofi omi si aojipo amafi won ile shop wa tabi office wa odaju

30/04/2022

Ogun Inu runrun
Ewe rerinkomi die,ati ewe imiesu pelu iyo obe die ao gbo awon ewe na papo awa fi iyo obe die si ama mu

11/04/2022

Awe bi danu
Ewe ege Gaga mesan lona meta aogun ni mesan lona meta yen ama we lojo kokan fun ojo meta....

02/04/2022

Aku odun awe gbogbo ile awon ise todara ninu awe tose sinu nbo wa laipe

11/03/2022

Ise ayeta
Ao wa eyin ibile kan pelu ito idaji kutukutu loa fise eyin naje odaju

24/02/2022

Oju orun to eye fo laifi apa kan ra won

21/02/2022

Aku ajale ooo

09/02/2022

OGUN ALANTAKUN
AO WA ODIDI ATARE KAN AOKI IGBALE EYOKAN SOSO BO INU ATARE NA AO WAFI ATARE NA KO OWU ALANTAKUN TI YIO BO GBOGBO ARA ATARE NA AOWA FI NKANKAN YO ATARE NA SINU APE IJOGUN AOJO ALO KUN NA DADA AOFI FO EKO TUTU MU LEKAN NA ODAJU...

Want your business to be the top-listed Beauty Salon in Ojo?
Click here to claim your Sponsored Listing.

Category

Telephone

Address

Alafia Estate
Ojo
1980