Emmanuel ADUN EDE
live program in broadcast
Happy birthday to me and my daughter today 14 is our day
Iṣẹ Iranṣẹ Pẹlu Agbara
02 Sep. 2025
LUKU 9:2
[2] O si rán wọn lọ iwasu ijọba Ọlọrun, ati lati mu awọn olokunrun larada.
[6] Nwọn si jade, nwọn nlà iletò lọ, nwọn si nwasu ihinrere, nwọn si nmu enia larada nibi gbogbo.
Akiyesi pataki ninu bi Jesu ṣe ran awọn eniyan jade ninu ibi kika yii ni wipe kiiṣe nkan kan pere lo ran wọn lati lọ ṣe. Jesu ran wọn lati lọ waasu ijọba Ọlọrun, ekini. Jesu tun ran wọn lati lọ ṣe imularada awọn alaisan. Ninu ẹsẹ kẹfa a rii bi wọn ṣe ṣe imusẹ awọn nkan ti Jesu ran wọn. Eleyi sele kii Jesu to lọ si ori igi agbelebu. Ibeere pataki ni wipe lẹhin igba to jinde njẹ eyi naa ni Jesu ṣe. Iwe mimọ fihan fun wa wipe iṣẹ iranṣẹ Jesu iṣẹ iranṣẹ pẹlu agbara ni. Ise iranse ti onigbagbọ n ṣe iṣẹ iranṣẹ Jesu naa ni. Idi eyi ni Jesu sọ fun wọn wipe ti won ko ba ti gba agbara won ko le jade lọ lati ma se iṣẹ ti oun ran won nitori pe iṣẹ to ran won naa ni lati waasu ijoba Ọlọrun ati lati mu awon eniyan larada.
Idi ti a fi n so eleyi ni ki a le mọ iṣẹ ti Jesu ran wa ki a si le mo iru igbaradi ti a nilo ati awọn ohun elo ti a nilo lati ṣe iṣẹ naa. Ti a ko ba gbagbo wipe Ọlọrun le lo wa fun iṣẹ rẹ ni ọna yii ti a ba n gbadura naa a ko ni reti idahun ni ọna yii.
JOHANU 14:12
[12] Lõtọ, lõtọ ni mo wi fun nyin, Ẹniti o ba gbà mi gbọ́, iṣẹ ti emi nṣe li on na yio ṣe pẹlu; iṣẹ ti o tobi jù wọnyi lọ ni yio si ṣe; nitoriti emi nlọ sọdọ Baba.
18/08/2025
PLUS ONE TODAY 18 /08 EMMANUEL JOSHUA MORIENIKEJI HAPPY BIRTHDAY TO YOU LONG LIFE AND PROSPERITY IJN
14/06/2025
Click here to claim your Sponsored Listing.
Category
Contact the business
Telephone
Website
Address
Osun