ASIRI awonbabaawa
your health is the most important to you
OSE Aworo
Odindi Tangiri kan
Ewe abamoda
Ewe anu
Ewe aje
Ewe Ela
Ewe oparun
Eyin ororo
Aopa Tangiri ni pansa
Aofi abamoda tele
Leyin naa aoko ewe yoku lelori
Aowa Fi ewe oparun soke awon ewe naa
Leyin naa aofi eyin ororo lelori
Aowa Fi ewe oparun bo eyin naa
Leyin naa ni aode pa
Aowa GBE sinu ILE ti atigbe siwaju shop wa aotun Fi ewe oparun boo
Aowa da yerupe le lori mole,,, fun alaye kikun 09015445520
21/08/2025
Fun eyikeyi Ogun Arun Ara,,,tabi eyikeyi ibere Lori awon inkan Miran,,,09015445520
OGUN IKO
Ebamiwa Lagidi tiwon findana,
Die kiejo ninu ibikan,,leyin,
Tiebajotan efi aseejoo kiewabu ogeere epo
Pupa si
Kieropapo daada,,kieni tonwuko naa maala
Laaro losan ati laale,,,,, ( Koda kiwonfise eyan
Eledumare yio mu kuro)ejowo ebami share,,
Kesi comment. Yioje fun yin Lase eledumare,,,
Fun ibere,09015445520
RIP mukaila senwele
OSE YIWULO FUN AWATI ANTAJA LARIN OJA TABI GBA ISE
Toobariwipe inkan seedie toosakiesipe
Ooriisegba tabi OJA oya rara
Yara kiose ISE yi,,,,,kokinse OGUN OWO,OO
Loowa ibiti wontindana aaro ( BII ABE ILE) Ti efin re sinseesoke
Yara figiko gbogbo jankariwo tobari nibe
Kiosi poomo OSE dudu daada kodarapo
Leyin naa kiofi ike funfun Kan TABI inu AWO
Kekere kan,, kiosi SE adura si daada
Koowagbe sibikan Tiidire ofinikanle ( pelu ogo olohun Oro re gbodo yato LARIN OJA NAA)
Jowo bami ,,,share,, Kosi comment,, Omaha JE fun yin,, fun alaaye Tabi ibere,,09015445520
OGUN OJU TONWOBAIBAI TABI TIKORORAN DAADA
Aolowa omi iru ogidi,,
Alubosa aayu toopodie
Orogbo totobi die meta
Pelu atare kan
( Aogun gbogbo re papo,,,,aoda sinu omi iru ogidi yen )
Aogbekale di ojokeji kofitoroo daada leyin naa
Lodililo,,,,saabiologun yioje fun yin Lase eledumare,,,,,,,jowo bami share Kosi comment
Ojuonireledewao,,,fun awon inkan miran,,09015445520
BEYAN BATENKAN MOLE TABI,,,,,ESE BASADEDE WU,,
Aolo wa igbe ewure toya lojuwa,,aosa tiyiogbe leyin tobagbe aolo papo mo Ori amo,,,aomofira ESE yen pelu ogo olohun yiofa
Tonasepe ESE yen baaloju eonifi Ori poo
Eemalo igbe ewure yen nikan ti eosimaa kuusi
Oju ESE NAA,, pelu ogo olohun yiogbe
Bami share nitori olohun,,,( yioje fun o )
Fun ibere,,,,09015445520
20/01/2025
OSE tafinmu,we OSI danu ,,, OSE tafinmu,we OSI danu
Ao lowa OSE dudu pelu ewe imiesu fun fun ,topodie
ao riwipe aagbo daada Omi tobajadenbe ni aopomo OSE dudu daada,,,,aosise adura si ,leyinna lodi Lilo,,,asilefi fo gbogbo inu shop WA,, Tabi inu Ile ti angbe pelu ogo olorun yioje funyin,,,,,,,( jowo bami shere,,re kosi coment pe Amin)Kosi eniti koleelo,,,,fun alaaye,,Tabi awon inkan miran 09015445520,,
Click here to claim your Sponsored Listing.
Category
Website
Address
Oyo