Yara Agbara Inu Laye Wa
Contact information, map and directions, contact form, opening hours, services, ratings, photos, videos and announcements from Yara Agbara Inu Laye Wa, Health/Beauty, Hamadiyya Road, Sango Otta.
ATUDE TODAJU
*Ewe Ajeobale tutu ojoo
*Epo obo
*Enu-opire
*Eso-iwerenjeje(Oju Olongbo)
*Ose Aganyin
Ao lo gbogbo awon Ero'nja yi papo ninu odo ti yi o kunna dada ao wa ko óse na sinu ike funfun ao ma we ni araro pelu kainkain ibile tuntun...
Akiyesi....Idi óse yi ko gbodo kanle mo......
Lati owo emi Oludasile egbe Agbara Inu laye wa
OSHOLE TODAJU FUN ILÉ KIKÓ
Ao wa opolo gbigbe kan,pelu ewe ijoku gbigbe 16,Odidi Atare 16,awo igala ao ge si 201,epo obo tofe dada ao wa jo papo ao ro sinu sere ao lo gbe ko si ibikan ti o ti ni kanle mo,ao ma fi foko mu ni aro ati ale.........
Majemu ise yi ni ki e dupe fun eledumare........ Lati owo emi Oludasile egbe Agbara Inu Laye wa.
OFIN EGBE AGBARA INU LAYE WA
1.GBOGBO OWUN TI A BA SE NINU YARA YI A FE KO JE IMULE AWO TI A KO FE KI ENIKENI MA LO SO LEYIN FUN ENIKENI
2.A O FI AYE GBA KI AMA BU RAWA NINU YARA YI
3.A O SI FI AYE GBA KI AMA RI AWON ADMIN EGBE YI FIN
4.ISE TI ABA FE FI SILE NINU YARA YI KI O JE ISE TI ATI DAN WO RI TI O DAJU
5.AKO DE FI AYE GBA ISE INU YARA OMIRAN SINU YARA YI
6.IPADE EGBE YI O MA WAYE NI DEDE AGO MEJO ALE NI GBOGBO OJO ISINMI TI AMO SI SUNDAY
7.NI GBOGBO IGBA TI ABA FE MA FI OGUN SILE NINU YARA YI NI KI A MA WA NI IBI TI O BA DAKE RORO NI TORI KI A LE MA GBO OWUN WA DADA
8.AO DE FI AYE GBA IPOLOWO OJA TABI STIKER TI KO BA ILANA INKAN TI A SE NINU YARA YI MU
9.ASI FE KI AMA SORO SINU YARA YI LOREKORE
10.ASI FE KI AMA RI ARAWA GEGE BI ENI APONLE.
KO JU BAYI LO AMO ENIKENI TIO BATI TA PA SI OFIN EGBE YI OWUN TI OJU RE BARI NI KI O FARA MOOOOO.
Eni ti o ba mo nipa ewe ati egbo ki o fi number re sile ki a gbewon si WhatsApp
AWORO TODAJU fun eni ti'nsise ijoko
Ao wa ókun lona oko,ao wa mu wa le ao je ki o rin wonu ado ató ti ati yo gbogbo awon idoti Inu re layi fe atekun sinu ado ato na ao wa bu iyo óbe pupo si pelu adi niwonba ao wa gbe ko sinu office wa...............
Ise todaju ni.....
Ki Awon Ero'nja po ko ni ogun,ashiri ni ogun
ATUDE TODAJU
Ao wa efun,osun,edu ao lo papo mo ose dudu ni iwe ekanso ninu ile iwe ni ale patapata ti ao sini jade mooooooo..........
Ashiri yi wa Lati owo emi Oludasile egbe Yara Agbara Inu Laye wa
ATUDE RPOMISE AND FAIL TODAJU
Ao wa epo obo to fe dada pelu ata ijosi to po die ao wa ge ninu epo obo yi ao gun mo ata ijosi ao po lose ao wa ko si Ori epo obo toku ao gbe pamo fun ojo meta leyin ojo keta ao ma we larolaro..........................ise todaju ni
Lati owo emi Oludasile egbe Yara Agbara Inu Laye wa.....
ATUDE TODAJU
Ao wa ewe tude ojoo,egbo tude ojoo,ao lo papo mo ose dudu,ao ko sinu fitila oloju merin ao wa te Odu osa meji si Oju ose na ao wa bu iyere osun sinu iho kankan ao ma bu we leyin ojo keta........
Ise yi koju bayi lo Lati owo emi
Oludasile egbe yi....
26/06/2021
IMULE AWON AGBA TODAJU
Ao wa ako alangba metta,eyin ororo meta,ogede omini meta, pelu atare meta,ao we ako alangba kankan ni a*o funfun,pupa ati dudu sinu isasun gege bi o se wa ninu aworan yi ao jo ao wa lo kunna dada ao ma fi oti lo laro ao mafi epo pupa la ni alale.
Lati owo emi Oludasile egbe Agbara Inu Laye wa,mo fi Ifa bura ise to daju ni
Click here to claim your Sponsored Listing.
Category
Culinary Team
Attire
Contact the business
Telephone
Website
Address
Sango Otta