Prince oyelami chief atayese ogun ibile tio daju
Asiri imon nipa ewe ati egbo todaju
Isora awon agba
Opolo aye kan,iye ako apa igun kan,ao ka iye yi ao fi bo opolo yi lenu odi inu agbada aofi atare kan si odi jijo leyin re ao lo ao fi sin gbere meta meta si ejika otun ati osi odaju ๐ฏ
Any infection cure ๐ค๐คท๐ฑ๐ฑ๐๐ค๐คท
Ewe efinrin,ewe efinrin,ewe ewe iyalode pupa,ao gbo gbogbo awon ewe yi po dada ao wa see ao ro sinu ike kan ao mon mun ni aro ati alee kosi iru infection nan okunrin ni o obinrin nio yio lo odaju dada ire chief atayese ๐ฌ๐ญ๐ณ๐ฌ๐ฏ๐
U can vist us in Ghana๐ฌ๐ญ๐ฌ๐ญ๐ณ๐ฌ๐ณ๐ฌ๐ฎ๐ช๐ฎ๐ช๐น๐ฌ๐น๐ฌ Ghana ni awa anything u need ๐คท๐ค๐ค?
Aworo nla nbo loju onan tio daju ero yio po koda yio su eyin gan ๐ฒ๐ณ๐๐ฅฑ๐ค๐ง๐งโ๐ฆฑ๐ฑ๐งโ๐ฆฏ๐ถ๐โน๏ธ๐คพ๐ด๐๐๐๐๐ฏ๐ฒ๐ฎ๐ช๐ฌ๐ญ๐บ๐ธ๐พ๐น๐น๐ฌ๐ณ๐ฌ
Afunje tio daju ๐ฏ๐ค๐๐ณ๐ฒ
Ito idajo ti ao ti fohun si eniyan ao to sinu Ike kan ao pa omo onile kan si ati osun awa de pa fun 7day leyin ojo yi ao dasi inu koko ti afi jogun ati ewe ogbo,ewe amuninuye,padi atare kan ao jo po eniti abafun je kotun fiwa sile mon ๐ฏ๐ค๐๐ฉโโค๏ธโ๐จ
Isoye tabi afi ha ikan si ori iwe tabi keu๐ฏ๐ค
Opolopo eso iyeye atare kan ao jo po at.........oju glass lao ti mon la pelu gbolohun re ni aro kutu odaju๐ฏ๐ฒ๐ณ๐๐ค๐ฏ
U can WhatsApp me or msg.e๐คท๐ฏ๐๐
20/06/2024
Owo ti afimun ole ti yio mag ale๐คท๐ฏ๐๐
21/02/2024
Ogun ibon,asimun,ki asasi ma ran mi tio daju ๐ช๐ฏ๐๐๐ฒ
13/02/2024
Apere ogun ๐ฏ๐ฏ
EYINI ETO TI OGO ENIYAN FI UN BUYO TODAJU
IKODE META
EWE OLA PUPO
EWE SAWEREPEPE TUTU
ABELA FUNFUN KAN
ABELA PUPA KAN
ABELA BLUE KAN
OSE EYIkEYI
AWO TABI IKE FUNFUN
SISERE
Aogun gbogbo awon erojayi po mon ose aowako sinu awo tabi ike funfun aowaki awon abela metetayi bo inu oseyi
N:B
Ti abati fewe oseyi aoma tan inaa si awon abelayi aosima gba adurasi ki atobu oseyi leyin naa aolofiwe leyin ti abawetan aofi owo (Hand ) pa inaa yi ..
Iseyi daju debiwipe ti wonbati gba ogo eniyan tele lesekese ni olohun yio gba funwa pada
Iseyi dara fun awon olorin , politician , oniseowo, onisowo , ati awon ti wonfe du ipokan tabi ominran
Ki ari daju wipe a gbe oseyi si aye mimon
Ti obinrin baunse inkan osu ki omase de idi oseyi ooo
Omoti kobatipe ogun odun komase lo iseyi ooo ๐by chief atayese ๐ฌ๐ญ๐ณ๐ฌ๐ฏ๐ค
07/02/2024
Epe tio daju ๐ช๐ฏ๐ฅฑ๐ฅฑ๐ฏ๐ฏ๐ฒ
Click here to claim your Sponsored Listing.
Category
Telephone
Website
Address
Tema