CAC oke adura by prophet James
At off adebowale ondo road
02/06/2023
Gbo iwo tori Amin se, olorun ba gbogbo ipinu ota je lori aye re losu ati lodun ni oruko nla jesu Amin
06/11/2022
Gbo iwo tori Amin se, olorun tun gbogbo ijoko awon igba okunkun ka lori ogo aye re ni oruko nla jesu Amin
Gbo iwo tori Amin se,edi aye ko ni mo ni oruko nla jesu Amin.
God is Good all the time
Ifihan ki awon elere sata gbadura dada ki won maba padu akinkanju osere meta ninu won ki odun yi to pari,ifihan
06/07/2022
Gbo iwo tori Amin se, olorun yo mu o rin irin ajo ogo losu yi ni oruko nla jesu Amin
Prophecy prophecy let all Nigeria be prepared for dangerous sickness, may almighty God protect and guard us in Jesus name amen
01/07/2022
Gbo iwo tori Amin se,losu keje yi olorun so gbogbo imo okunkun di asan lori aye tomotomo ni oruko nla jesu Amin
27/06/2022
Gbo iwo tori Amin se,gbogbo agba jowo okunkun lori aye re ati ri awon omo re ati lori ise re, olorun alagbara fi ina orun tun won ka ni oruko nla jesu Amin.
13/06/2022
Gbo iwo tori Amin se,alagbara omiran to ni ohun ko ni fun o ni aye lati ri ogo aye re lo,ni oruko nla jesu ko so agbara re danu lori aye re amin
Click here to claim your Sponsored Listing.
Category
Telephone
Website
Address
Ondo Road
Akure