Tito TV
A lover of God creating content
l share relatable contents Daily prayers in Yorùbá and English that can help your day by day life journey.
remember the best is yet to come 🙏🏻
11/09/2026
Gbogbo ìwọ to tẹ Amin sì Adura yi 👇
Ní ìkòríta ko yemi mọ tí ẹ wà iranlọwọ láti Orun a dìde fún yín ẹ o ri Àánú àti ojú rere Ọlórun gba láṣẹ Èdùmàrè 🙏🏻🙏🏻🙏🏻
Gbogbo ìwọ to rí Amin se gbogbo ohun to lérò ní réré kí Osù yí tó parí ma ṣẹlẹ̀ láyé rẹ Àmín loruko Jesu Kristi
Gbogbo ìwọ alaye to ní ore ọ̀fẹ́ láti rí imọle Alaye lóni so wipe
Ògo ní fún Ọlọ́run lókè ọrùn 🙌🙌🙌
Gbogbo ìwọ abiyamo ní mo fé kí ẹ ṣe Amin sì Adura yi 👇
Nígbà tí ilé ìwé bá wọlé àwọn ọmọ rẹ O ní di àwátì láṣẹ Elédùmarè Àmín 🙏🏻
10/09/2026
Nínú osù yí wá pàdé Oluranlowo Ayanmo rẹ láṣẹ Èdùmàrè Àmín
Gbogbo ìlérí ayọ tí Ọlọ́run ti ṣe fún emi ati iwo toún wo video yí kí ọdún yi tó parí yo wá sí ìmúṣẹ láṣẹ Elédùmarè Àmín Tito TV fans
10/09/2026
Subscribe to get exclusive benefits:
https://www.facebook.com/61560650134025/subscribenow
Gbogbo ìwọ to rí Amin ṣe ẹ ní di ológo àná Amin loruko Jesu Kristi 🙏🏻
Jiji tí ẹ jí ní òwúrò yí ìwàláàyè Ọlọ́run Olódùmarè yo má ba yí gbé ilẹkun ìbùkún yo shi fún yín tomotomo láṣẹ Elédùmarè Àmín 🙏🏻
Te Àmín sì Adura yí
Gbogbo ẹnikẹni to pinnu láti fi Ọ sęsin Ọlọ́run Olódùmarè a fí irú ènìyàn bẹẹ sęsin láṣẹ Èdùmàrè Àmín
Click here to claim your Sponsored Listing.
Address
Lagos Harbour
11011