ASEDA
esu aseda .I am traditionalist .esu Nation..
★ ★
bami share post yi fún anfaani ọpọ eniyan ogun ayé koni borí rẹ amin
(1)Awon eniyan má ń lérò wípé tí wọn ba dárúkọ ELEGBE ọmọ wọn ró wípé àwọn ẹlẹmi òkùnkùn ọmọ ni wọn soro lorie, rárá o kori bẹẹ.
Ọpọ ènìyàn to wá láyé ni elegbe ọmọ irin ajo ọmọ kọ̀ọ̀kan lati ode orun wa silé ayé lo yàtọ tọ síra wọn
(2)Bi emere Ọmọ sewa nínú Obìnrin bẹẹ naa lowa nínú Ọmọ Ọkùnrin, kódà egbe AMUTORUN ỌMỌ OKÙNRIN tún man lágbára pupo ju ti Ọmọ Obìnrin lọ ní gbogbo ọ̀nà ao máa mẹ́nu bá die ninu isesì àti àwọn ìwà wọn
(3)Bi eniyan báni Ọmọ ọkùnrin tó sije Ọmọ elegbe AMUTORUN WÁ SAYE, láti kèkére Ọmọ yí ni etí máa rí àwọn nkan kaye fi lára rẹ yóò máa ṣe bí àgbàlagbà yio si maa sọ̀rọ̀ bí àgbàlagbà yio maa mú inú ìyá rẹ dùn,
Iṣesì yí náà wá lọdọ àwọn ọmọ elegbe AMUTORUN WÁ SAYE TOJE ọmọ Obìnrin náà, ẹyin ìyá tiẹ̀ bá bí irú àwọn Ọmọ bayi edakun emaa listen 👂 sì ọ̀rọ̀ won daada nitori awon omo yí yio maala àwọn àlá tótó bí ju ọjọ́ orí wọn lọ
bákan náà wọn yio si maa rí rán daada VISION, Nítorí bie ba n listen 👂 siwon won YIO MAA salaye gbogbo ẹ fún yín kie sì máa báwọn mójú to irin ajo ayé wọn
(4)Awon omo elegbe AMUTORUN WÁ SAYE toba je Ọkùnrin ipò nla ni wọn man gbewa sáyé Ìṣe toba tí yàn láàyò latode orun wá tó bá ti dele ayé tó sì ń ṣeé láti ẹnu ìṣe yí ni ògo rẹ yio tí buyo rẹpẹtẹ,,
èyí toba yàn orí Ọba aládé láti kékeré rẹ ni eo tí máa ríi lára rẹ, eyiti oba yàn orí Apesin gbogbo ènìyàn ní wón ó má listen sì orí rẹ yio si ko egbe jọ rẹpẹtẹ irú àwọn ènìyàn bayi lè má ń bá nìdí oselu Politicians, Pastor, Wòlíì, Alufa
ńlá, Olorin ńlá, Onisowo ńlá, Ẹ,T,C
(5)Ninu awọn Ọmọ Ọkùnrin ELEGBE AMUTORUN WÁ SAYE, àwọn kan wà nínú wọn tó jẹ́ wípé Oloja Obìnrin ni wọn, àwọn miran iranse aje, àwọn miran jagunjagun, Àwọn miran iranse àánú, àti bẹẹ bẹẹ lọ.
Awan ọmọ wa oni seru ayé oo amin.
Fún àtúnṣe lori ọrọ ayé rẹ spiritual and physical
👇
Call/WhatsApp
08033784377
Fadipe Aseda care
1. Bi eniyan baje Onisowo nla ti oja re man din ku laimo eni to n yo oja re, bi o ba mu Ekuru funfun ki o roo papo mo iyo tabi oyin, ki o fon Ekuru yii si gbogbo oja yi, oja re koni din mo, yóò si ta daada.
2. Bi eniyan ba saba maa n je Ekuru daada, asiri ikoko nipa oro ara re yio maa han sie, wa ma ri isipaya nipa oro aye re loju orun daada.
3. Kosi iseda Irawo ti ko le je Ekuru tabi lati fi se Sahara fun eniyan, gbogbo iseda Irawo ni Ekuru wulo fun.
4. Bi eniyan ba saba maa nje gbese tabi owo kii duro sowo eniyan, se Ekuru yii ko po, ki o ha fun gbogbo eniyan ki o si gbe iyoku losi aarin Oja, ki o lo fi se Sahara fun awon atewo gbore, waari iyato daada.
5. Ni ayajo ojo birthday re, ti o ba koko se Ekuru yii fun gbogbo eniyan ti o si pepe adura si boya Alfa re tabi Pastor re, ki won se adura fun e, waari iyato rere ninu aye re.
6. Bi eniyan ba sese ra ile (land) ti o fe kole sori e, ti o ba koko se Ekuru yii pelu oyin ati iyo ti o fi roo daada, bi o ba se bee bi emeta ki o to bere ile naa, arisiki ati ibukun yoo duro si ori ile yen, gbogbo eni toba gbe inu ile naa koni mo inira, awon emi okunkun kankan kosi Le duro sori ile naa laelae.
7. Bi eniyan baje elegbe ọmọ ti o ba nda Ekuru sinu odo nla nla sungbon ri wipe odo ti eja bawa ninu re loda Ekuru naa si o, gbogbo nkan yóò dero fun e, ayaafi ti ogun idile ba po fun eniyan kii je ki ọmọ ologo o tete rise.
Ogo de emi pin konije ipin emi ati iwo 🙏
8. Asina owo, e wa Ekuru funfun meta, ori, sugar lebu lebu, ao run Ekuru yen sinu abokan, ao yo ori yen lori ina, ao wa da si inu Ekuru yen, ao fi owo ro papo, ao wa bu sugar yen si, ao tun ro papo, ao wa lo fon si oju ona ti ese nrin... O sise asina daada pelu
Bi eyi baje anfaani fun o, share re ki elo miran je anfaani re.
Humanity's
Health is our concern!
Gbogbo wa
Amari Anu GBA lase edumare
🙏🙏
FUN AYEWO LORI
OHUN KOUN
FADIPE ASEDA CaRE
08033784377
21/08/2026
★ ★
Moti soro koja lori ala yi laimoye igba sugban fun anfani eyin ti esitun nbere ibeere lori e
Ti Obinrin ba nla ala pe won ba ohun ni ibalopo loju orun
ITUMO:- iru Obinrin be yio pe ki o to ri oko abi ki ope koto bimo kosi ni ni akojo oun rere ogun ikorira, ijakule, ati amubo ma po fun iru obinrin bee.
Iwo obinrin be teramob igbinyanju ki osi se iwadi lórí Oro aye re bóyá oko Orun, egun idile, epe ajogunba, afowofa, tabi awan ika eniyan lowa ninu okunkun toun ta offa sinu imole aye re.
Ti Okunrin baun la ala pe ohun ba Obinrin ni ajosepo loju orun
ITUMO:- iru okunrin be yio ma mu amubo Obinrin tabi koma ni akojo oun rere atun mafa ikorira lawujo iwo na to àwọn oni mimo lo ki oro aye re leba ni ojutu
Aimoye eda towa ninu isoro yi loti gba awe ati adura lori isoro buruku yi sugban kaka kosan otun nburu si ni hummm omo iyami mafi akoko aye re sofo mo jade si oro aye re ni
Ema simigbo o mioso wipe ki ama gba adura lori isoro wa o sugban adura wa loto igbiyanju wa loto, aabo oro laaso fun omo luwabi tobade inu re adi odidi aditu oro fun awan ologban ati oni laakaye.
Ti Okunrin ba la ala pe ohun ba Obinrin sun loju orun amo tiko dasi ara
ITUMO:- Okunrin na yio ri owo daada ni asiko igba yen sugban ti koba mura koni ri nkan rere tofi owo yi se toka si.
*AKIYESI PATAKI*
ki lo lefa ki eyan ma la iru ala yi ?
Tobaje Obinrin ni inkan bi meji lo man saba fa akoko ninu ki o je elegbe omo ki o ti ni oko ni orun ti awon Yoruba npe ni (oko orun)
Ekeji Ogun idile atun ma faa ti won mafiun gba gbogbo oore ayo eda ati bebe lo
Sugban fun Okunrin nkan bi meta lo maun fa Akoko o sese ki ohun na ti ni Iyawo ni orun ti won ti Jose igbeyawo
Ekeji Ogun idile atun ma fa lati fi gba oore eda bakan na.
Eketa ti okunrin bato ni aya ti kosi ni ti arare batikun ti kosi tete ri ibi dasi atun ma fa ki okunrin mada si ara ati bebe lo
ITUMO AWON ALA
1,Ti o ba lala pe oungbo ohun egungun loju orun abi egungun nle o
ITUMO - Idamu awon elemi okunkun ni kunfun adua dada ati igbiyanju
2,Ti o ba lala pe aja ngbo o loju orun
ITUMO -Iroyin buruku nbo lati ilu okere abi si eni ti osunmo e mura dada
3,Ti o ba lala pe o jade lati inu saare loju ala
ITUMO - Isegun iku ojiji loje fun e kun fun adua dada
4,Ti o ba lala pe o sun ti omo tuntun loju ala
ITUMO - Idunnu nla lonbo lodore kun fun adua dada
5,Ti o ba lala pe o ri igbin tonfa loju ala
ITUMO - Idamu ranpe ni kun fun adua Dada.
6,Ti o ba lala pe o fi esere te igbin mole ti o fo
ITUMO - Wa da owo (business) po pelu alagidi eyan kun fun adua dada
7,Ti o ba lala pe o ga gogoro ju bi o tiwa tele lo
ITUMO - Aisan ti o le ni sungbo koni fa iku fun e kunfun adua daada
8,Ti o ba lala pe o na omore loju ala
ITUMO - Kun fun adua ki omo na maya oniwakiwa tabi omo buruku
9,Ti o ba lala pe won fi ida be o loju ala
ITUMO - Ijanba lati owo ota re leyi je kun fun adua dada
10,Ti o ba lala pe o ri oga loju ala
ITUMO - Awon eniyan won o ma se o lanu kun fun adua Dada
★AKIYESI★
Ti o ba la ala toju agbara re lo kun fun adua ni ki o si to awon oni mimo lo fun itumo re ati ona abayo.
Ma se maro Ala Asiri nipa oro inun ile re fun enito sunmo e gbinyanju kope àwọn oni itumo ala abi eni ti oma wipe oma nipa ala ni ki osoro Ala re fun.
11. Ti o ba la ala pe o gun eshin funfun loju orun
ITUMO:- Waa di oba tabi olori ni awujo kan Ala rere ni kun fun adua daada ki awan ari ogo siwaju ologo mase gba iwaju moe lowo.
12, Ti o ba la ala pe o je obi loju ala
ITUMO:- Mojele oju ooru ni eleyi je kun fun adua daada masi dake lori oro aye re.
13, Ti alaboyun ba la ala wipe oun ri ojo to su loju orun
ITUMO:- irorun ni yio je fun alaboyun na ti o bafe bimo kun fun adua daada
14, Ti o ba la ala pe o ko igi jo loju orun
ITUMO:- Wahala yio joko jeje wasi ti orun bo kun fun adua daada
15, Ti o ba la ala pe o mu oti tabi emu loju orun
ITUMO:- kadara re yio yi pada si buruku kun fun adua daada
16, Ti o ba la ala pe o ri ijapa loju orun
ITUMO:- Wa se alabapade alanu ti yio fun e ni owo sugban awan eni ibi yofi igaga di oju alaanu re koni rina se e ni oore kun fun adua lori oro aye re
17, Ti o ba la ala pe o fun wara ni omu malu
ITUMO:- Ore nla ni eleyi je fun e kun fun adua daada
18, Ti o ba la ala pe o ri osan ti o ti pon daada loju ala
ITUMO:- Bukata re yi o biya kun fun adua daada
19, Ti oba la ala pe o ri agbado yala o je sunsun tabi eyikeyi ninu agbado
ITUMO:- Wa ri owo laipe kun fun adua ki awan eni ibi ma gba iwaju moe lowo.
20, Ti oba lala wipe oun rin laiwo bata
ITUMO:- oshi ati idaamu ni mura lori oro aye re.
Mobe olohun fun gbogbo iwo ti oni anfani atika oro yi ti osi bami share re wipe Ogun idaamu konije tie amin.
Fún àtúnṣe lórí ọrọ ayé rẹ spiritual and physical
👇
Call/WhatsApp
08033784377
Fadipe Aseda care
★ ★
KINI AUN PENI ÒGÚN ẸTÌ GAN ATI WIPE ONA MELO NI ÒGÚN ẸTÌ PIN SIN KILOUNFA OGUN ẸTÌ SINUN AYE AWA EDA ÈNÌYÀN?
Bami share post yi fun anfaani opo eniyan Ogun aye Koni bori rẹ Amin.
Moti soro koja Lori topic yin sugban fun anfaani eyin ti esi tun beere ibeere Lorie
👇
ONA MEJI NI ETÍ PIN SI
(1) Eti alakoko ni eyi ti ogbajumo ju ti ọpọlọpọ eniyan mo wipe kí ènìyàn gbero lati dawọ le nkan ki nkan na ma ṣee ṣe
Ògún kan ni eleyii lọtọ ti ènìyàn báun koju ogun eti yi gbogbo nkan ti ènìyàn bá fẹ dáwọle nkan yen koni bosii
Awan ika ẹdá sí maun lo ogun yi láti fi koba irin àjò ayé ẹdá
Kódà ibi ti eleyii lagbara dé ti elomii ninu awan ti ògún yi báun da láàmú toba dé ibi tí yóò ti ri ona abayo sí ìsoro ayé è koni pada de ibẹ mo
Moti so ọpọlọpọ ọrọ lori eleyi ni part 1.
Bi ose Bami share post yi fun anfani opo eniyan ogun aye koni bori re amin.
(2) Eti elekeji eleyi na je ogun nla ninu aye eda eniyan, ati okunrin ati obinrin ni ogun buruku yi maun sele si
Aoni ṣe dede àgbákò laye wa amin.
ọpọlọpọ obinrin ati okunrin nii oun koju iṣoro yìí tii ko síi tètè wá ona abayo kuro ninu ìṣòro yìí eleyi pada wa di ogun ati egún aye raye sinu idile wọn.
Eleyi ma ùn jeki obìnrin tabi okunrin mu amuba ọkọ tàbí aya kosi bíi iru wọn sele nii owó 💰 lọwọ to tabi je gbajumọ láwùjọ to won kii nii ibujoko
*ONA TÍ ỌKUNRIN FILÈ MỌ PÉ OGÚN ETI YI NDA AYE OUN LÁÀMÚ*
*Iyawo iru won kii ùn bawon kale
*Obìnrin ma ùn ku mọ elomii wọn lori
*Okunrin awon eda yi kii nii ori obinrin
*Obìnrin awọn ẹda yi kii lori okunrin
*Irọ nii obìnrin fii ma ùn ba okunrin toba ni ògún yi ló
*Iro ni okunrin fi maun ba obinrin toba ni ògún yi lo
*Ala lila nipa ìbálòpọ̀ wa ninu apere ti eni tobaun koju isoro yi na ama ri eyii sile fa kii ijakule ma bawon ninu adawo le wọn.
*Aya orun kii ùn fẹ kí wọn nii Iyawo bẹ sini obinrin kii ùn gba tiwon bíi ose lè wu komo.
* Oúnjẹ oju orun ma ùn pọ fún wọn nii gbogbo igba .
Etc.........
*ỌNA TÍ OBÌNRIN FÍ LÈ MỌ PE OGUN ETI NDA OUN LÁÀMÚ* .
Ibalopọ oju orun nii gbogbo igba leyin tii obaji tan gbogbo ara ati tútù
Bii ki wan ma lala wipe awan dawo le nkan nkan na ko yori t**i ti wan fi taji tabi ki wan ma se irin Ajo loju ala Lai de ibi ti wan un lo t**i ti wan fi ma taji saye
Wón kii tètè ríi okunrin tii won n'ifẹ síi
Okunrin tii won ba n'ifẹ iru okunrin bẹ kii ùn nifẹ won ìró ni okunrin fi maun bawọn lo
Agídí nii won fi maùn tii arawọn síi okunrin lọrùn
Amubo ọkọ ma ùn pọ jù fún wọn
Leyin tii okunrin bati bawon nii Ibalopọ gbogbo ọrọ ajé (business) okunrin bẹ yóò daru.
Tori wipe Emere elekisa pọjù ninu wọn.
Etc.....
*AWON ONA TII OGUN ETI MA UN GBA WỌNU AYE EDA*
Ogún ẹtì maùn wọnú ayé ẹdá latara aṣọ 🧥 tabi bàtà 👞
Latara Spong tii won fii wẹ ọmọ nii ikoko awọn amokunseka ma ùn lo lati fa ogun yi sinu aiye ọmọ
Latara sisin planceta nii ona tii otako irawo ọmọ
Latara Aini àkíyèsí
Latara orukọ ọmọ, njẹ oruko tii oso ọmọ rẹ papọ mọ aseyori orire ọmọ rẹ bíi??
Epe lẹnu obi, ogun idile, Egun idile e.t.c
Bíi eda koba mọ akosejaiye rẹ tii osi ùn se nkan tii otako akosejaiye rẹ odidandan kii ogún ẹtì wọnú ayé rẹ.
Egun idile ati epe ajogunba maun fa ogun eti sinu aye eda.
Etc ...
Ogun buruku koni jẹ temi ati e amin.
Fún àtúnṣe lórí ọrọ ayé rẹ spiritual and physical
👇
Call/WhatsApp
08033784377
Fadipe Aseda care
★ ★
Bami share post yi fun anfààní ọpọ ènìyàn ogun ayé koni borí rẹ Amin.
Mogbadura fún gbogbowa wipe ifaseyin koni je tiwa amin
Ti aba ùn la awọn ala wanyii ejeki atèté mura si ọrọ aye wa pẹlu igbiyanju.
Bíi obalala pe oun ri tàbí sá ìgbín 🐌 ìjàpá, alákàn nii ilé nle
Itumo:- Ifaseyin nii múra lori ọrọ ayé rẹ
Bíi obalala pe ofegun 🪜 akaba sugbon oorigun doke t**i ti ofi taji s'aye
Itumo:- ati dé ibi gíga fún ee yóò fẹ nira diẹ múra lori ọrọ ayé rẹ
Bíi obalala pe oun ka ata🌶️🫑 tabi oun ra ata tabi oun lo Ata
Ìtumọ:- ipọnju nii múra lori ọrọ ayé rẹ
Bíi obalala pe owa ni inu primary sch too otijade nii ọpọlọpọ odun seyin
Itumo:- ifaseyin nii múra lori ọrọ ayé rẹ
Bíi obinrin tàbí okunrin ba lala wipe oun nii íbalopo loju oorun leyin tii otaji saye tan gbogbo oju ara-re ti tutu
Ìtumọ:- Ifaseyin nla ni mura lori ọrọ ayé rẹ
Bíi obinrin ba lala pe oun ríi okunrin tii kii ùn se ọkọ ee loju ayé gẹgẹ bíi ọkọ ee loju ala
Itumo:- ipinya yóò fé ṣẹlẹ nínú relationship e múra lori ọrọ ayé rẹ
Bíi obalala pe oun mu oti tabi ogogoro tàbí siga lójú ala
Ìtumọ:- aye tife da irin ajo aye e ru tètè múra lori ọrọ ayé rẹ
Bíi obalala pe oun wẹ nii ita gbangba tii ọpọlọpọ awọn eyan hun wo ee
Ìtumọ:- mura kii àṣírí e mase tú.
Bíi obalala pe oun dede ba arare ninu family 🏠 house nii gbogbo igba
Ìtumọ:- ifaseyin hùn bọ latara ogún ìdílé
Bíi obalala pe oùn gburo igbe Aja 🐕 tabi aja ùn le ee loju ala nii gbogbo igba tabi aja bueje
Ìtumọ:-idamu lati ọwọ ọta nii tètè múra lori ọrọ ayé rẹ.
Bíi obalala pe oun sha owó 💰 loju ala tabi won ùn fún ee lówó lójú ala
Ìtumọ:- oda owó 💰 tabi gbese nii.
Bíi obalala pe egungun ùn le ee nii gbogbo igba
Itumo:- ogun idile yóò fẹ sọ é di ẹni ẹyin múra lori ọrọ ayé rẹ
Ala buruku koni se mọ wa lára àmín.
Fún àtúnṣe lórí ọrọ ayé rẹ spiritually and physically
👇🏻
Call/WhatsApp
08033784377
Fadipe Aseda care
18/08/2026
Aseja asiribibo owo kia kia
Ewe tannapowo
Ewe etiponla
Ata ijosin eyo 16
Ao lo gbogbo re papo ao Fi se ponmo maalu tia ge si 16 je lepo niyo ao fi iru woro si . tio ba jina ao shadura si ao je
Fadipe Aseda care
08033784377
Ìwúre to all Parents 👨👩👧👦✨
Eépà Òrìṣà!
Baba Arúgbó, mo dúpẹ́ fún àwọn òbí wa for they care for me, guide me, sacrifice for me, and help me grow.
May they be blessed with strength, wisdom, peace, happiness, and good health. May I always honor them, listen to their guidance, and show my love through Ìwà rere.
Àṣẹ.
Ọ̀rìṣà Eépà!
📸: Ẹfúnṣetán offers her Ìwúre to Òrìṣà Nlá, asking for blessings for his parents.
(Excerpt from the book: ÒRÌṢÀ NLÁ INVOCATIONS: A Prayer Guide for Young Yorùbá Minds)
New words from this Ìwúre:
Ìwà rere — Good character; being good and kind to yourself and others.
Mo dúpẹ́ — I give thanks.
Àwọn òbí — Parents.
© Fadipe Aseda care u
Ọjọ́rú (Wednesday)
04/08/2026
EMERE FUNFUN (PURE WHITE SPIRIT) 🤍
PART ONE
🌟 Emere Funfun je awon emi (spirits) ti ki se aburu tabi ika.
🌟 Imole (light) ni won je, won ko si nise pelu okunkun (darkness).
• Opolopo eniyan ti iseda won je Emere Funfun maa n ni oju anu ati ife si eniyan.
• Won kii saba huwa ika, toripe emi to n dari won ko feran aburu tabi iwa buburu.
• Awon emi yi maa n se iranlowo pupo fun awon eniyan ninu igbesi aye.
• Nigbati omo egbe won ba wa si aiye gege bi eniyan, won maa n duro leyin re gidigidi.
• Iranlowo ati itileyin ni okan lara awon nkan pataki ti awon emi yi maa n se.
• Iseda eniyan to je Emere Funfun gbodo maa gbe igbesi aye rere.
• O dara ki won maa se rere si awon eniyan ni gbogbo igba.
• Ki won ma se ohun to le mu awon emi tabi egbe won binu si won.
• Toripe ibinu awon emi to n dari won le fa wahala ati idena fun won.
• O tun se pataki ki won maa ran awon eniyan to sun mo won lowo gege bi agbara won se gba.
• Eyi maa n je ona kan ti awon egbe won fi tun n se iranlowo fun won.
EWO (FORBIDDEN) 👇
• Ko dara fun iseda eniyan to je Emere Funfun lati darapo mo egbe keegbe.
• (Bad or evil organisation).
• Toripe aburu nla lo maa n je fun iru awon eniyan bee.
NOTICE 👇
• Ilosiwaju ati ore (fortune) maa n jina si Emere Funfun to ba n se ika tabi aburu.
• Awon emi to n dari iru eniyan bee maa n binu gan-an.
• Eyi le fa ifaseyin ati didena ore ninu igbesi aye won.
• Opolopo Emere Funfun ni won wa si aiye pelu ise pataki (message) kan.
• Toripe won kii de aiye lasan gege bi awon eniyan miiran.
• Opolopo won si maa n ni ase inu (spiritual power).
• Agbara yii ni won fi n daabo bo ara won.
• Ati awon eniyan to sun mo won gege bi ebi (family) ati ore (friends).
• Nitori eyi, o ye ki won maa lo agbara won ni ona rere ati fun anfaani awon eniyan.
.........
MADAWO DURO BAYI NA MATUNTE SIWAJU NIGBAMI, GBIYANJU KIO FOLLOW MI TORIPE ANFANI SIPO TIWATUN BAPADE LODOMI.
(WhatsApp 08033784377
• Asiri po ni abe irawo yi ti a ko le so tan, Iwo ti o ba fe mo nipa asiri to pamo si abe irawo re pelu alaye lekunrere, Message me privately.
.........
• FUN IWADI LORI IRAWO RE TABI AKOSEJAIYE RE MESSAGE MINI WHATSAPP LORI NUMBER TOWA LORI PROFILE MI.
• if you find this interesting, and you are looking for the rest part, explore my page and follow for more
• 👍Like, comment, and share
Fun iwadi ATI ayewo
Contact my washap
08033784377
Fadipe Aseda care
Click here to claim your Sponsored Listing.
Contact the business
Telephone
Website
Address
Lagos