ASIRI AWON AGBA

ASIRI AWON AGBA

Share

We created this group to assist people in all ways of life like.... Any kind of sickness, marital

11/08/2025

*ASIRI TI AFI NRA ILE TODAJU*
🅰o lo wa opolo gbigbe mewa, orogbo mewa, obi gbanja ifin mewa, obi gbanja ipa mewa, odidi atare mewa, oga ooye kan, gbogbo owo ti ahunna, kowe olori dudu kan. Ao ko won sinu ape bi mose toyi, oga ooye yi loma kanyin. Ao jeki oga yi gba awo awon owo yi dada, ao wa da owo yi le ori oga yi, ao wajo, ao lo kuna dada (ao lo step akoko towa loke sugar onikoro mo), ao ro sinu ado seere, ao ran a*o egungun ni apo (inu re lama gbesi). ao mafi oti shinapp lo lararo tabi kia mafi fokomu.
*AKIYESI PATAKI*....... Ti aba tilo ise yitan, ao lori ado ati a*o egungun yen mo ori ile ti abara yen kia mabaa ma lala ri egungun.

16/07/2025

*AWENU TOYANRANTI*
🅰o lo wa ewe iyalode funfun eyokan, orogbo toni epo lara, kahun bilala die, ao lo won papo, ao fi ose iwe ekan ko, ao we ose yi ni ale. Ti abati we ose yi tan, ao wa mu sibi epo pupa kan.

16/07/2025

*OSE ATUDE ASINA TIPATIPA TOTUN SISE CASHOUT*
🅰o lo wa opolo ijokun ooye kan, egbo tude, epo obo, ata ijosi 16, ao gun won papo, ao fi ose ko, ao fi Bintu de dada, ao gbe opolo ooye miran si isale ike funfun, ao wa ko ose yi bo mole, ao fi ikode kan gun ose yi lori, ao gbe pamo fun ojo meta, ao bere wiwe re leyin ojo keta. Bi omo yahoo bawe ose yi yio gba owo gidi.

14/07/2025

*IMULE AWON AGBA*
🅰o lo wa isu ogirisako tutu, ao ge kekeke sinu ape, ao gbe ori okete kan le pelu odidi atare kan legbe re, ao jo, ao walo kuna, ao ro sibi kan. Tio badi ni ale, ao bu die sinu ike, ao bu epo pupa le lori, ao wala.

14/07/2025

*ASIRI BIBO KIAKIA*
🅰o lo wa ori oka to lase lenu, ao fi tele ape, ao to owo eyo ti ko luju meta yika re, ao ko epo ijebo si legbe, ao fi eyin adire ibile kan si, ao wa da ewe sawerepepe toni itana lori bo lori (tutu tabi gbigbe), ao ko ewe inabo bo mole (tutu tabi gbigbe), ao wa fi ewe abamoda oni gaga meta kan tutu bo, ao gbe odidi atare kan tope le, ao wa da ewe ola topo bo mole, ao wa jo, ai lo kuna dada, ao ma fi oti schinapp li lararo kua to soro si enikeni tabi kia mafi fo eko elewe mu.

12/07/2025

*OSHOLE OWO NLA*
🅰o lo wa owo otun elegbede, ako ijapa nla kan, ape tuntun. Ao fi ijapa yi tele ape, ao gbe owo elegbede yi tii legbe, ao wa to ori olongbo mefa to nirun dada yika won ninu ape, ao ko ewe ola bo lori, ao ko odidi atare mefa le, ao wa da ewe anu bo mole, ao jo, ao lo kuna. Agogo merin si marun idaji ni lilo re pelu oti lai tii soro si enikeni. Tested and Confirm ni ooo

12/07/2025

*APOTA TODAJU*
🅰o lo wa eyele kan, ao fi abere oporo 16 gun ni gbogbo ara, ao gbe sinu ape, tio bati ku, ao ko ewe semolapa semolese (ewe segun sete) bo mole pelu odidi atare kan, ao jo, ao lo kuna, ao wa ro sinu igo funfun tabi ike funfun, ao mafi ro ekuru funfun je. Enikeni toba nro ibi siwa yio ma ni accident tabi kio mafi ese gun egun, ti yio siwu

11/07/2025

Big shout out to my newest top fans! 💎 Ojurelafinwowo Halifa Kolade, Ogouchoro Kéyindé

Drop a comment to welcome them to our community, fans

11/07/2025

*OSE ATUDE AJAIDE TO GBONA/ OTUN DARA FUN OMO YAHOO*
🅰o lo wa egbo tude tutu, ewe tude tutu, epo obo, egbo egbesi tutu, egbo ipeta tutu, ewe sawerepepe tutu, ao gun won kio kuna dada, ao wa fi ose Ghana popo dada, omi agbon lama fipo po dada, ao ko sinu ike funfun, leyin ojo keta ao ma buwe lararo tabi alale.

09/07/2025

*TURARI AWORO*
🅰o lo wa ewe ajeobale turu oojo, epo obo, eru alamo, imi ojo, ao gun won papo dada ti yio di turari, ao sa si abe ile kio figbe dada, ao ko sinu apo asunwon a*o funfun (idire ko gnodo kanle mo), ao ma fin lararo pelu adura
*ADURA*
Pelu awon ero nlanla, alaje, oloro, ki turari yi wa ma dari won wa bami laye yi timo wa, ki ero mawo witiwiti, ise aworo ni mofe ran iwo turari yi, awon eniyan nlanla, awon eniyan gidi ni kio ma wowa s**o mi.

09/07/2025

*OGUN TI AFI NYANJU EJO TOBA LAGBARA/ TABI TI AFI NTU EJO KA*
🅰o lo wa eku eliri, iru pete ti ko niyo, owu dudu ati owu funfun. Ao wa ninu ile ni ihoho omoluabi, ao san iru yen mo ara eku yi dada ti ara re koni han mo rara, ao wa gbe dani, ao wa so wipe..... Igbodi miramiramira*3, okunkun birimubirimubirimu*3, oro ...ati... bayibayi tani yio bi erin yii bi efon, nigbati ile yio fimo eliri lasan lobi, ko soro nibe mo, oro.... ati... ti won nfa laarin ara won, ti won gberawon losi court lola ko soro nibe, ki won da ejo na nu ni.
Ao wa mo we ni owu imule, t**i ao fi wetan lao mape ohun yen si. Ao walo si aarin igbo, ao da ile ikan kekeke yen legbe, ao wa kibo, kia to ju sinu re, ao tun pe ohun yen si. Ao ma lole, awon ikan yen yio ti mole bo mole.

Want your business to be the top-listed Beauty Salon in Lagos?
Click here to claim your Sponsored Listing.

Category

Telephone

Address


Iyana Ipaja
Lagos