ASIRI ATILA EDA

ASIRI ATILA EDA

Share

IMOLE SHEEU Hl

07/07/2022

ASIRI NIPA BATA TANWO

OHUN NI AMONRAN MI FUN GBOGBO EYIN OLOLUFE IMOLE SHEEU FUN TOSU YI

FUN IBERE LORI ORO YI PEMI

CALL OR WATHSAPP 08143776104

Bata duro fun aseyori eda. Bata duro fun igbe aye ojo ola eniyan. Nitori naa bata kii se n kan ti eniyan maa n fi owo yepere mu rara. .

1. Ti bata ba sonu e je ki a fi gbogbo nkan wa.

2. Ti won ba gba bata lo loju ala mase fi owo kekere mu.

3. Ti bata ba ja loju ala mase gboju kuro. O lewu.

4. Mase ya bata wo o le tibe wonu ogun lo.

5. Mase ya enikankan ni bata re. Won le ti be gba ogo ola re lo.

6. Maa kiyesi bata re ki o to kese boo. Ti o ba fura si bata naa ma se kese bo o.

7. Mase je ki omode tabi agba duro le ori bata re. Won maa n fi ba ogo aye eni je.

8. Ma se maa bo bata senu ona re paapaa ti o ba n gbe ile binukonu.

8. Maa kiyesi bata re lòore koore. Ma se je ki o maa soju dele . Kii je eniyan laseyori laye.

9. Mase je ki won ko bata tiwon sori ti e. Won maa n fi teri ogo eniyan ba ni.

10.Ma se je ki won maa gba bata re riboribo kiri. Won maa n fi gba oore aye eni danu ni.

11. Mase je ki won fi bata ti e se ball. Aye eni yen ni won n gba o. Gbagbe pe omode ni.Omode miiran wa to je elemi okunkun to si je iyalaya ika.

12.Sora fun ebun bata. . Mase woo lesekese. Toju fun o kere ju osu kan ki o to woo.idamu le gba ibe wole.

13.Mase je ki won fi bata re rori o paapaaa lori oke abi nibi adua.

14.
Ma se bo bata sile anyhow paapaaa nibise ninu ijo ati ninu ile ti a n gbe.

Ki ele yi ma je ebun oni yi

24/06/2022

Jummat Mubarak

22/06/2022
09/12/2021

EBU OSO GBAWA ONI 5 MILLIONS TODAJU👇👇

Oromon adie tikoju bi ojo méta lo
Ewe papasan eyo 9/7
Ewe egele 9/7
Eyo atare 9/7
Afomo.ajade 9/7
Gbogbo owo tana nilu tabawa
Okan omo aja
Okan ijakpa kekere
Ewe apada pupa ojo 9/7
Iru ori afi
Basi eran agba kan
SISERE RÉ OO
Ao KO gbogbo awon kan n'a sinu eye kowe aye ao gbe sinu ikoko tutu ao jopo toba jotan ao kuna tobakuna tan ao pa eje pepeye ao fi ejeye die fipo ebu ao tusa sinule kofigbe dada tobagbe tan ao pi ebu n'a si ona 9/7 ao ma lo ni ojo 41 la mamalo eyo kokan T**i ti ebu n'a mafitan ni ago kan oru si ago mefa idaji ni lilore pelu eko lafilo oo kotolu ago kan osan pelu ogo olorun ani alejo tomawa toju owo siwa lowo ti koni padawamo laye sugbon 5 MILLIONS lomawabe pelu ase. Olorun
Sugbon kagbiyanju kani imule pelu ajeogun ati eyonu gidi Lara katodawo le ise yi oo
IKILO NIPA ISE YI RÉ OO
Ao gbodo ba obirin oloyu su lojo ti alo iseyi ooo ayijebe haaaaa onewu ooo
ENITI KOBAYE KOMAMI SORO

OGUN IMULE AGBA TODAJU👇👇
Gbogbo ifu inu aja
Ewe mafiowo kan omomi ojo
Ewe oriji ojo
Atare méta odidi
Ao jopo ao mafi epo pupa fila ni ale ao gbodo jade sita mon oo
Walayi ise Toni agbara ni ti eyan bani oso todaju tobalo imule yi kotodawole iseye walayi adupe ayo

EYONU AYE 👇👇
Ewe oriji
Ewe omisimisi pelebe
Afara oyi
Atare odidi kan
Ori ologbo kan
Jijopo ao mafi fokomu ni aro kutu pelu adura wa

ASEJE OSOLE OWO TOMAGBEWA👇👇
Odidi okete kan
Ao gesi ona 16
Ijosi koniye
Ewe aje koniye
Ewe anu koniye
Afomo ishi
Iyere 16
Ao fise okete n'a je
Ago kan oru ni amaje oo esewa kogbondo kale a*o fufu ni ao fibora tabaje lowo
Ni ojo keji si ojo keta asiri wa mabo si owo 200.000 naira
EJE KAGBIYANJU DAN ISE YI WO MY ,ALFA ABASS IMOLE SHEEU ORISA BI AFIN

Want your business to be the top-listed Beauty Salon in Oyo?
Click here to claim your Sponsored Listing.

Category

Telephone

Website

Address


Maniya Ibadan
Oyo