Fatex Aloba building construction.

Fatex Aloba building construction.

Share

Contact information, map and directions, contact form, opening hours, services, ratings, photos, videos and announcements from Fatex Aloba building construction., Health/Beauty, Oyo.

23/10/2024
Photos from Fatex Aloba building construction.'s post 06/02/2024
Photos from Fatex Aloba building construction.'s post 06/02/2024

See something

Photos from Fatex Aloba building construction.'s post 03/02/2024

CALL FATEX

02/02/2024

KAFIYESI OOOOO OLU OF IFON ORULU KINGDOM

21/11/2023

View years ago

21/11/2023

The Ooni of Ife’s only son, Prince Tadenikawo’s birthday photos have raised mixed feelings on social media.

A number of Nigerians had things to say about the outfit the little boy’s mum, ex-queen Naomi, chose for him.

One netizen wrote: “This picture will start causing headaches in that palace now. God will continue to protect you, Tade.”

21/11/2023

*ILE ÀYÉ ASÁN*

Ni ọjọ́ kàn, Ọmọkùnrin kan sọf ún baba rẹ wí pé, baba mi mo ri ọmọbìnrin kan tí o ní ẹwà púpọ, o si wu mi lati fi se àyà, baba dáhùn o ni:- *Kò sí wàhálà,* sùgbọ́n o, mo fe ki o fi ọmọ naa hàn mí kí n le ba ọ ba a sọrọ.

Baba ati ọmọ gba ọdọ ọmọbìnrin naa lọ, ni ìgbà tí wọn dé ọdọ arẹwà naa, *baba dáhùn ọ sọ wi pe:-* irú iwọ kii se ẹni tí o yẹ lati fẹ arẹwà obìnrin yii o, sùgbọ́n irú emi gángan lo yẹ lati fẹ ẹ!

Bayii ni wàhálà sọ̀ kalẹ láàrín baba ati ọmọ, Ni awọn méjèjì ba ko ẹjọ lọ sí ọdọ adájọ.

*Adájọ ni ẹyìn méjèèjì ẹ n so ni ọdọ arẹwà obìnrin náà, bi adájọ se ri obìnrin yii o sọ wi pe:-* ẹyìn méjèèjì ẹ ko yẹ lẹni ti yoò fe arẹwà yii, sùgbọ́n àwọn adájọ bii témi yìí ni o ye ki n fẹ arẹwà yi!

Bayii ni ija tun sẹlẹ láàrín baba ati ọmọ pẹlú adájọ, ni àwọn mẹtẹta ba tun ko ẹjọ lọ sí ọdọ *Ọtun Oba* nínú ìlú, *Ọtun Oba* dáhùn o ni ẹ n so l'ọdọ arẹwà náà, bayii ni *Ọtun ọba* náà tún sọ wí pé: ẹyìn mẹtẹta ko yẹ lati dúró tí arẹwà yii óò, bi ko se wí pé emi Ọtun Oba l'oyẹ lati fẹ ẹ, *bayii ni wàhálà tun sẹlẹ láàrín àwọn mẹrẹrin,* ni gbogbo wọn ba tún ko ẹjọ lọ sí ọdọ Oba ìlú, *kabiesi dáhùn ọ sọ wi pe:-* ẹ n so l'ọdọ arẹwà náà, *bayii ni Kabiesi naa dáhùn wí pé:-* arẹwà yii Olórí Oba ni o yẹ ki o jẹ óò, eyin mẹrẹrin e ko yẹ lẹniti yoò fẹ arẹwà yi, *sùgbọ́n emi Kabiesi 'o yẹ lati fẹ ẹ,* bayii ni wàhálà nlá tún sọkalẹ sí àárín àwọn mararun oooo...

*Arẹwà náà wa dáhùn o sọ wi pe:-* nnkán ti à o se ree óò, èmi yíò s'áré ni iwájú yin, gbogbo yin e o ma l'émi bọ ẹnití ọwọ rẹ bá kọkọ kan mi ohun gangan ni yíò f'ẹmi ooo...

*Bayii kabi'esi* bọ Ade kalẹ ati Irùkẹ̀rẹ̀ ati ilẹkẹ ọrùn, *Ọtun Oba* náà bọ gbogbo nkán ara rẹ naa kalẹ

Bakanna ni Adájọ ati baba ati ọmọ wọn bọ gbogbo nkán arawọn kalẹ nítorí arẹwà obìnrin yii!

Arẹwà sáré gba ọnà ilé rẹ lo, ni ibití koto nlá kan wa, gbogbo wọn náà sáré tẹle, ni ibi ọgangan kòtò yi, bayii ni awọn mararun já sí inú kòtò óò ti wọn ko le jáde mọ, ni arẹwà wa dúró ní etí kòtò ọ sọwipe:- *njẹ ẹmọ mi?* Gbogbo wọn dáhùn won s

Want your business to be the top-listed Beauty Salon in Oyo?
Click here to claim your Sponsored Listing.

Category

Website

Address


Oyo