Sheik onike

Sheik onike

Share

Contact information, map and directions, contact form, opening hours, services, ratings, photos, videos and announcements from Sheik onike, Health/Beauty, Saki.

16/05/2026

NAFILAH BASMALAH FUN BIBO ASIRI KIAKIA

Nafilah yin dara pupo gidi fun eniti olohun bani kole gbinyaju re tikoya lazy person...Nipa asiri wakiah timofikale opolopo awon eniyan ni won private chat mhi wipe ko easy fun awon Koda awon Kan sope awon komo kewu but nafilah Yan easy fun wa gidi otunwa yara biya bukata eyikeyi asiri eyin agbalagba etiamo mofe ki a danwo ti olohun bani karise Walahi talahi kotope ojo meje bukata naa ma biya ni kiakia Walahi talahi.......

14/05/2026

ASIRI WAKIAH FUN OWO NLA

ILEYA BONUS

Mofi Asiri yin kale fun gbogbo wa komaje Anfani fun gbogbo awa ti Olohun bani ale gbiyanju adura Walahi talahi amase Odun irorun ti asiriwa Simabo lonakona talero tele Amari owo gidi Walahi talahi Asiri todamiloju gidi……
Asiri Suratul wakiah fun asina owo gidi fun eniti Olohun basope o bale gbiyanju re ti abati kirun asuba tan a o wa ju kafura eyokan senu o wa bere adura towa ninu iwe yin
Astegfrulaha 100
Lahilailalahun 100
Asalatu 100
Yah jamjafanuru 1000
Suratul wakiah 3

A o mase adura yin pelu kafura towa lenuwa a o sima gbe ito re mhi t**i taofi pari adura yin taba tipari adura yin a o yo kafura yan lenu a o pamo di ojokeji….tobatundi ojo Keji a o tun se adura yin pelu kafura to seku yan naa t**i ti kafura yan mafi yo tan ojo ti kafura yan bati yotan laoto ni se adura yan mo.....Aleri kafura yan lo bi emeji tabi emeta bati jubelo koto yo tan tobati yotan a o ni se adura Yan mo..a o se Sara re bi abase lagbara si..amari owo nla gidi idaji ni sise adura naa olohun agba adurawa...

07035001257 Whatshap nomba

Alfa Muhammed onike ❤️

12/05/2026

ILEYA BONUS

ADURA WAKIAH FUN BIBO ASIRI OWO KIAKIA

Edakun eyin agbalagba Inu midun bi e se share asiri mhi kakiri but nkan tikoda nibe wipe ti awon eniyan ba share asiri mhi won a tun pa oruko mhi re kuro nibi asiri Yan elomiran le fi photo re tabi oruko re Koda bayan..Walahi talahi aniyan timo fi fi asiri kale oyemi pelu olohun aniyan tafida group yin kale Walahi talahi lati fi ran arawa lowo ni most especially awa omo islam ki amo titobi olohun latara alquran kamowipe asiri nbe ninu alquran kosi nkan toto oruko olohun ati alquran laye...mi oni ki e ma share asiri mhi but edakun ema fi lujibiti tabi ki ema fi ni awon eniyan Lara.....asiri lukudi Timo post enikan send re simi wipe Alfa Kan send si ohun....ohun wa sofun Alfa Yan wipe koba ohun se alayere Alfa Koda ohun lohun mo seri bi iwa awon eniyan seri....edakun emafi asiri Timo ba post se 419.....tobalo Lona aito inshallah kunfayakun re olohun ma bami yo kuro.....bijahi rosuli 🙏

ADURA WAKIAH FUN BIBO ASIRI KIAKIA...is laodin.....

10/05/2026

ADUA LATEEF FUN AANU GIDI

Asiri Lateef yin sise fun aanu Olohun lonakona gidi Ti Olohun bani ki ale ma gbiyanju adua yin Walahi talahi onakona ni aanu Olohun yoo ma sele siwa Lona airotele odaju pupo.aro kutukutu lama n se Iseyin ti abati kirun asuba tan a o wa tray tabi awo toba flat a o wa fi oyin Han Khatimi yi Sinu awo tabi tray yan leyinna a o wa gbe siwaju wa a o wase allahumo soli alah muhammad waselim 100 leyinna a o wa daniyan aanu lodo Olohun leyinna a o wa se yah Lateef 313 tabi 1111 tabi 4444 leyin taba tipari Lateef yan a o wa fi asalatu 100 parire a o wa fi ahon la khatimi ti afi oyin la sinu awo tabi tray yan a o fi ahon la opari bee lamama se adura yin lojojumo edakun ejeki gbiyanju asiri yin ejeki a se fun okere ju 14days or 21 days or 41days ki awo arati Olohun mada funwa iseyin daju pupo gidi olohun ajeki oje funwa allahumo amin....

ADUA WAKIAH FUN OWO laodin ileya bonus....

07035001257 whatshap number

Alfa Muhammed onike

05/05/2026

ASIRI HANTU OSHOLE OWO LUKUDI FUNFUN TOYANJU PUPO

ASIRI HANTU OWO LUKUDI FUNFUN KAN TODAJU tikoni repercussions kankan Walahi talahi ojo meje lama filo hantu yin a o gbodo sunmo obinrin inshallah mo yonda re fun birthday gift mhi.....adura yin ni mofe ise timofi kale yin Walahi talahi asiri Inu ile ni ola ife eyin eniyanmi infact eyin omo iyami ninu Islam ola ife yin ni...asiri yin ti aba rise ti idiwo kobasi ni arawa tojewipe Alfa tobaba wa hantu iseyin tikobase abosiwa Walahi talahi amadupe fun olohun..bi oshole asiriowo senbe ninu ogun dudu beeni naa lonbe ninu oruko olohun TODAJU lodo awon agbalagba Alfa ebami Dan asiri yin wo but ki a to se asiriyin agbodo lo ibtol shir tabi Tude oni hantu ati ose dada a o si gbodo sunmo obinrin fun iye ojo Tama filo iseyin...Ao Han ayah Yan ni iye onkare ni 3333 sinu opon ola toma pe pere pere a o wa fo pelu Omi ojo tabi Omi tomo dada a o wa fo sinu ike 2ltre Kan a o gbe pamo (edakun ejeki hantu yan pe ni iye onkare 3333 tikobape isere koni dahun dada oo)..leyinna a o wa gbogbo owo ti Ana ni country ti angbe ni Nigeria nibi 5 10 20 50 100 200 500 1000 a o ko gbogbo awon owo yin a owa oga aye a o jeki oga yin kogba gbogbo awo owo yin pata tobatigba awo owo yin tan a o wa ju oga yin ATI gbogbo yin sinu ikoko a o wa jo pelu odidi atare Kan Toba ti jotan a o lo kunna dada a o wa di ebu or etu ti a o joyin a o ma fi lo hantu yin diedie lojojumo fun ojo meje larolaro.....A o wase adura re lojojumo 1111 tabi 313 ni a o Mase adura but kise tulasi ni adura re but tabatule gbinyaju adura re omajeki iseyan tun lagbara si gidi ni...iseyin dami loju dada motise fun aimoye awon eniyan tiwon si dupe...Walahi talahi ayewa gbodo yato Koda koje businessman Contractor Etc connection mawa lonakona ni odaju kosi eniti kolese iseyin ebami danwo nikiakia ki e funmi labo olohun ajeki o je funwa🙏🙏

07035001257 Whatshap nomba

ALFA MUHAMMED ONIKE❤️🙏

01/05/2026

HAPPY NEW MONTH

ASIRI HANTU OWO LUKUDI FUNFUN KAN TODAJU tikoni repercussions kankan Walahi talahi ojo meje lama filo hantu yin a o gbodo sunmo obinrin ati OSE TI AMA FI FO ORI FUN ENI TI ORI RE MA N TAKO TABI FUN ORI TOBURU😀 TI ENINA FIMA RI AYIPADA RERE NINU AYERE😀🙏
Enitojewipe Ori ntako kogbe nkan se dada ri ninu ayere inshallah fun birthday gift mhi.......Nipa Alfa to share asiri mhi to yo oruko mhi kuro towa mgbe photo re si...moti soro sinu page Alfa naa wipe komase be mo.....tori iru nkan bee Koda rara kije ki asiri je.....anybody lole share asiri komaje anfani fun gbogbo aye but edakun ema fi lujibiti ooo tobafilujibiti olohun Mamu e tulasi.... inshallah....olohun agba adurawa 🙏

29/04/2026

IFERAN TOYAWERE

Muhabahyin lagbara pupo gidi fun okunirin tofe ki obinrin nife
ohun tabi obinrin tofe ki okunrin nife ohun tabi enikan n binu siwa afeki inure korosiwa kobaje Oga si omose tabi oko si iyawo etc...ejeki a gbinyaju asiri yin olagbara pupo Koda ki oko ma binu si iyawo re ejeki ase iseyin tabi iyawo Banbinusi oko re ejeki ase iseyin funwon odaju pupo..

A o Han ayah Yan bosewa ninu iwe Yan sinu iwe funfun ni emeje a o ma fi oruko oko si oke a o ma fi oruko obnirin si isale a o wa fi kafura sinu tira naa a odi tira pelu owu funfun ATI dudu a o wa la ogede agbagba ninu a o fi tira yin sinu re a o wa we ogede agbagba yin ni owu dudu ati funfun a o wa Lori ogede agbagba naa mo eti odo tabi nibi petepete nibi tikigbe opari odaju pupo edanwo...

Alfa Muhammed onike ❤️

29/04/2026

IFERAN GBOGBO ENIYAN

Gbogbo eniti ikorira bawa larare tojewipe gbogbo ibi tobade awon eniyan ma n korira nibi gbogbo tabi okunirin tikori iyawo tabi obinrin tikori oko ejeki a gbinyaju iseyin Koda odara fun awon onisowo contactor musicians MC omo ile kewu tabi omoilewe omo ikose etc ti agbiyanju iseyin awon eniyan ma nifewa gidi ganni.....

A o Han gbogbo awon kewu towa ninu iwe yin sinu opon ola a o wa ewe sawerepepe tutu..ewe ewuro tutu ewe ogbo ewe birana tutu ewe omisimi pelebe a o wa fi Omi agbon gbo awon ewe yin a o wa fi ase se idotire danu a o wa fi Omi naa fo hantu yin a o wa da lofina sasorabia tabi six flower tabi Danduala Kan si a o wa ma fi para ni gbogbo igba odaju pupo...
olohun ajeki o je funwa 🙏

Alfa Muhammed onike ❤️

25/04/2026

ASIRI ADURA SURATUL FATIHI FUN OWO NLA ATI CONNECTION GIDI TODAJU PUPO...

Ki asiri yin maje birthday gift fun gbogbo eyin agbalagba ti e se adura funmi komaje Hadiyah funyin eyin agbalagba ti e se adura funmi........mofe ki e bere adura yin ni ojo Sunday Walahi talahi amari owo dada ise TODAMILOJU ni iseyin tiwa lowo mhi Walahi talahi lati igba timo wa ni secondary achool around 2010 close to 16yrs today ni mofi asiri yin dara die edakun ebami gbinyaju asiri yin odun ileya mbowa taba lese asiri yin ama dupe fun olohun bi asiko base lagbara to konile mowa.....Oru ni sisa iseyin ejeki a lotoju agbado funfun ati okababa funfun ki a mix re papo ki a bu iyo die si....a o ma gbe siwaju lasiko adura...A o wa ni mimo pelu aluwala a o fi lofinda oloru si arawa a o Yan Nafilah anabi adamo (Nafilah merin ) Nafilah akoko leyin Fatiah kuliuwalahun 10 Nafilah keji leyin Fatiah kuliuwalahun 20 Nafilah eleketa leyin Fatiah kuliuwalahun 30 Nafilah kerin leyin Fatiah kuliuwalahun 40 a o wa salamo a o se mukodimat leyin mukodimat a o wa bere SURATUL FATIHI eyokansoso lafe ke but ise Tao se ninu surah naa motise alayere sinu iwe Timo post yin edakun ejeki a fi arabale dada tabatipari adura kogbawa ni asiko pupo a o wa daniyan a o wa bu die ninu agbado funfun ati okababa Yan a o fi se Sara ni oru Yan naa tabi laro ojo meje lama fisa iseyin tabi jubelo Koda alemu ni lazimi gbigba adura wa Lara iseyin odaju pupo......olohun ajeki o je funwa 🙏
Note...Ti iseyin kobayewa e message me privately ma tun alayere se dada funyin....

Majemu iseyin ni ki o se adura funmi🙏🙏

HANTU LUKUDI FUNFUN TOJE OSHOLE OWO TODAJU.. drop soon...my birthday gift mo n reti re lodo eyin agbalagba. Long life and prosperity to me Abiola❤️

07035001257 WhatsApp nomba

Alfa Muhammed onike❤️🙏

Photos from Sheik onike's post 24/04/2026

Alhiamdulilahi Alhiamdulilahi 🙏
Alhiamdulilahi robil alamina 🙏
Today is my birthday....
Happy birthday to me
All is need is ur prayers lover 🙏

Im expecting my birthday gift
I will drop comfirm sirru for my birthday gift inshallah....

23/04/2026

Dis Saturday 25 of April is my birthday......in massive advance to me.....

inshallah ma drop awon asiri lorisirisi fun eyin agbalagba komaje gift fun birthday mhi......adura yin ni mofe....

ASIRI SURATUL FATIHI FUN ASINA OWO ATI CONNECTIONS......laarin ojo meje ama ri owo gidi...loading....

Alfa Muhammed onike ❤️

Want your business to be the top-listed Beauty Salon in Saki?
Click here to claim your Sponsored Listing.

Category

Website

Address


Saki